4 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭑﭒﭓ
106:1 (Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo
ﭔﭕﭖﭗﭘ
106:2 (Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru
ﭙﭚﭛﭜﭝ
106:3 Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii
ﭞﭟﭠﭡﭢﭣﭤﭥ
106:4 Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers