Surah Al-Fil ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Fil pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (5 Ẹsẹ — مكية). Al-Fil Gbọ, Al-Fil Itumọ, Al-Fil mp3, Al-Fil pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Fil

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
أَلَمْ تَرَ كَيْفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصْحَابِ الْفِيلِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Se o o ri bi Oluwa re ti se oro ijo elerin ni
أَلَمْ يَجْعَلْ كَيْدَهُمْ فِي تَضْلِيلٍ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Se ko so ete won di ofo bi
وَأَرْسَلَ عَلَيْهِمْ طَيْرًا أَبَابِيلَ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
O si ran awon eye nikoniko si won
تَرْمِيهِم بِحِجَارَةٍ مِّن سِجِّيلٍ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Won n ju won ni okuta amo (t’o ti gbana sara)
فَجَعَلَهُمْ كَعَصْفٍ مَّأْكُولٍ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
O si so won di bii erunrun koriko ajeku gbigbe
← 104 Al-Fil (105/114) 106 →
Kika Surah Al-Fil ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

105الفيل Al-Fil 📚 5 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Al-Fil — 5 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers