Surah Al-Kawthar ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Kawthar pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (3 Ẹsẹ — مكية). Al-Kawthar Gbọ, Al-Kawthar Itumọ, Al-Kawthar mp3, Al-Kawthar pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Kawthar

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
إِنَّا أَعْطَيْنَاكَ الْكَوْثَرَ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Dajudaju Awa fun o ni opolopo oore
فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَانْحَرْ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Nitori naa, kirun fun Oluwa re, ki o si gunran (fun Un)
إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ الْأَبْتَرُ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Dajudaju, eni t’o n binu re, oun ni ko nii leyin
← 107 Al-Kawthar (108/114) 109 →
Kika Surah Al-Kawthar ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

108الكوثر Al-Kawthar 📚 3 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers