Surah Al-'Asr ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-'Asr pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (3 Ẹsẹ — مكية). Al-'Asr Gbọ, Al-'Asr Itumọ, Al-'Asr mp3, Al-'Asr pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-'Asr

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
وَالْعَصْرِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Allahu bura pelu akoko irole aye
إِنَّ الْإِنسَانَ لَفِي خُسْرٍ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Dajudaju eniyan wa ninu ofo
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَتَوَاصَوْا بِالْحَقِّ وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won so asotele ododo laaarin ara won, ti won si tun so asotele suuru laaarin ara won
← 102 Al-'Asr (103/114) 104 →
Kika Surah Al-'Asr ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

103العصر Al-'Asr 📚 3 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers