3 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭑﭒ
103:1 Allahu bura pelu akoko irole aye
ﭓﭔﭕﭖﭗ
103:2 Dajudaju eniyan wa ninu ofo
ﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞﭟﭠﭡ
103:3 Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won so asotele ododo laaarin ara won, ti won si tun so asotele suuru laaarin ara won

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers