Surah Al-Humazah ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Humazah pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (9 Ẹsẹ — مكية). Al-Humazah Gbọ, Al-Humazah Itumọ, Al-Humazah mp3, Al-Humazah pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Humazah

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
وَيْلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni
الَّذِي جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin)
يَحْسَبُ أَنَّ مَالَهُ أَخْلَدَهُ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye)
كَلَّا ۖ لَيُنبَذَنَّ فِي الْحُطَمَةِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْحُطَمَةُ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh
نَارُ اللَّهِ الْمُوقَدَةُ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
(Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere)
الَّتِي تَطَّلِعُ عَلَى الْأَفْئِدَةِ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo
إِنَّهَا عَلَيْهِم مُّؤْصَدَةٌ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata
فِي عَمَدٍ مُّمَدَّدَةٍ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
(Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina)
← 103 Al-Humazah (104/114) 105 →
Kika Surah Al-Humazah ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

104الهمزة Al-Humazah 📚 9 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers