Surah Al-Ikhlas pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah Al-Ikhlas pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Ikhlas Itumọ. Surah Al-Ikhlas (Meccan) 4 Ẹsẹ.
Related
More Surah PDF
Surah Al-Ikhlas

ﭑﭒﭓﭔﭕ
112:1
So pe: "Oun ni Allahu, Okan soso
ﭖﭗﭘ
112:2
Allahu ni Asiwaju (ti eda ni bukata si, ti Oun ko si ni bukata si won)
ﭙﭚﭛﭜﭝ
112:3
Ko bimo. Won ko si bi I
ﭞﭟﭠﭡﭢﭣ
112:4
Ko si si eni kan ti o jo O." eyi ni a mo si “robbu-ssamowat wal-’ard wa mo baenahumo”. Idi niyi ti a o fi tumo “Allahu” si “Olohun”. Ninu ede Yoruba ko fee si itumo ti a fokan bale si fun oro-oruko nla naa “Allahu” afi lilo oro-oruko kan eyi ti awon Yoruba maa n lo ni ojoun ana fun “Olohun”. Sise bee si maa mu ariyanjiyan lowo. Nitori naa
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







