Surah Al-'Alaq ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-'Alaq pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (19 Ẹsẹ — مكية). Al-'Alaq Gbọ, Al-'Alaq Itumọ, Al-'Alaq mp3, Al-'Alaq pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-'Alaq

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
اقْرَأْ بِاسْمِ رَبِّكَ الَّذِي خَلَقَ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Ke (al-Ƙur’an) pelu oruko Oluwa re, Eni ti O da eda
خَلَقَ الْإِنسَانَ مِنْ عَلَقٍ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
O seda eniyan lati ara eje didi
اقْرَأْ وَرَبُّكَ الْأَكْرَمُ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Ke e. Oluwa re ni Alapon-onle julo
الَّذِي عَلَّمَ بِالْقَلَمِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Eni ti O fi imo nipa gege ikowe mo eniyan
عَلَّمَ الْإِنسَانَ مَا لَمْ يَعْلَمْ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
O fi imo ti eniyan ko mo mo on
كَلَّا إِنَّ الْإِنسَانَ لَيَطْغَىٰ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Ni ti ododo, dajudaju eniyan kuku n tayo enu-ala
أَن رَّآهُ اسْتَغْنَىٰ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
nitori pe o rira re ni oloro
إِنَّ إِلَىٰ رَبِّكَ الرُّجْعَىٰ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Dajudaju odo Oluwa re ni abo eda
أَرَأَيْتَ الَّذِي يَنْهَىٰ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
So fun mi nipa eni t’o n ko
عَبْدًا إِذَا صَلَّىٰ ۝١٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 10
fun erusin kan nigba ti (erusin naa) kirun
أَرَأَيْتَ إِن كَانَ عَلَى الْهُدَىٰ ۝١١
📖 Itumọ Ẹsẹ 11
So fun mi (nipa esan re) ti o ba je pe o wa lori imona (’Islam)
أَوْ أَمَرَ بِالتَّقْوَىٰ ۝١٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 12
tabi pe o pase iberu (Allahu)
أَرَأَيْتَ إِن كَذَّبَ وَتَوَلَّىٰ ۝١٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 13
So fun mi (nipa iya re) ti o ba je pe o pe ododo niro, ti o si keyin si i
أَلَمْ يَعْلَم بِأَنَّ اللَّهَ يَرَىٰ ۝١٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 14
Se ko mo pe dajudaju Allahu n ri (oun ni)
كَلَّا لَئِن لَّمْ يَنتَهِ لَنَسْفَعًا بِالنَّاصِيَةِ ۝١٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 15
Bee ni (Allahu n ri i.) Dajudaju ti ko ba jawo (nibi didi i lowo), dajudaju A maa fi aaso ori re wo o (sinu Ina)
نَاصِيَةٍ كَاذِبَةٍ خَاطِئَةٍ ۝١٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 16
aaso ori opuro, elese
فَلْيَدْعُ نَادِيَهُ ۝١٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 17
Nitori naa, ki o pe awon olubajokoo re
سَنَدْعُ الزَّبَانِيَةَ ۝١٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 18
Awa maa pe awon molaika eso Ina
كَلَّا لَا تُطِعْهُ وَاسْجُدْ وَاقْتَرِب ۩ ۝١٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 19
Rara o, ma se tele tire. Fori kanle (ki o kirun), ki o sunmo (Allahu)
← 95 Al-'Alaq (96/114) 97 →
Kika Surah Al-'Alaq ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

96العلق Al-'Alaq 📚 19 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Al-'Alaq — 19 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers