PDF —
5 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Qadr pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Qadr pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Qadr Itumọ. Surah Al-Qadr (Meccan) 5 Ẹsẹ.



5 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭴﭵﭶﭷﭸﭹ
97:1 Dajudaju Awa so al-Ƙur’an kale ninu Oru Abiyi
ﭺﭻﭼﭽﭾﭿ
97:2 Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Oru Abiyi
ﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆ
97:3 Oru Abiyi loore ju egberun osu lo
ﮇﮈﮉﮊﮋﮌﮍﮎﮏﮐ
97:4 Awon molaika ati Jibril yo si maa sokale ninu oru naa pelu ase Oluwa won fun gbogbo oro eda kookan
ﮑﮒﮓﮔﮕﮖ
97:5 Alaafia ni oru naa titi di asiko afemojumo

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers