5 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮈﮉﮊﮋﮌﮍ
111:1 Owo Abu-Lahab mejeeji ti sofo. Oun naa si sofo
ﮎﮏﮐﮑﮒﮓﮔ
111:2 Awon dukia re ati ohun ti o se nise (iyen, awon omo re) ko si nii ro o loro (nibi iya)
ﮕﮖﮗﮘﮙ
111:3 O si maa wo inu Ina elejo fofo
ﮚﮛﮜﮝ
111:4 Ati iyawo re, alaaaru-igi-isepe elegun-un, (o maa wona)
ﮞﮟﮠﮡﮢﮣ
111:5 Igba-ope ponponran maa wa ni orun re (ninu Ina)

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers