At-Talaq · 1/12
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Talaq
يَا أَيُّهَا النَّبِيُّ إِذَا طَلَّقْتُمُ النِّسَاءَ فَطَلِّقُوهُنَّ لِعِدَّتِهِنَّ وَأَحْصُوا الْعِدَّةَ ۖ وَاتَّقُوا اللَّهَ رَبَّكُمْ ۖ لَا تُخْرِجُوهُنَّ مِن بُيُوتِهِنَّ وَلَا يَخْرُجْنَ إِلَّا أَن يَأْتِينَ بِفَاحِشَةٍ مُّبَيِّنَةٍ ۚ وَتِلْكَ حُدُودُ اللَّهِ ۚ وَمَن يَتَعَدَّ حُدُودَ اللَّهِ فَقَدْ ظَلَمَ نَفْسَهُ ۚ لَا تَدْرِي لَعَلَّ اللَّهَ يُحْدِثُ بَعْدَ ذَٰلِكَ أَمْرًا ۝١
Yaaa ayyuhan nabiyyu izaa tallaqtummun nisaaa`a fatalliqoohunna li`iddatihinna wa ahsul`iddata; wattaqul laaha rabbakum laa tukhri joohunna mim bu-yootihinna wa laa yakhrujna illaaa any yaateema bifaahishatim mubaiyinah; wa tilka hudoodul laah; wa many yata`adda hudoodal laahi faqad zalama nafsha; laa tadree la`allal laaha yuhdisu ba`dazaalika amraa
📖 Ni Yorùbá
Iwo Anabi, nigba ti e ba fe ko awon obinrin sile, e ko won sile pelu sise onka ojo opo fun ikosile won. Ki e si so onka ojo opo. Ki e beru Allahu, Oluwa yin. E ma se mu won jade kuro ninu ile won, awon naa ko si gbodo jade afi ti won ba lo se ibaje t’o foju han. Iwonyen si ni awon enu-ala ti Allahu gbekale. Enikeni ti o ba tayo awon enu-ala ti Allahu gbekale, o kuku ti sabosi si emi ara re. Iwo ko si mo boya Allahu maa mu oro titun sele leyin iyen

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 1-3 — Surah At-Talaq

1يَا أَيُّهَا النَّبِيُّ إِذَا طَلَّقْتُمُ النِّسَاءَ فَطَلِّقُوهُنَّ لِعِدَّتِهِنَّ وَأَحْصُوا الْعِدَّةَ ۖ وَاتَّقُوا اللَّهَ رَبَّكُمْ ۖ لَا تُخْرِجُوهُنَّ مِن بُيُوتِهِنَّ وَلَا يَخْرُجْنَ إِلَّا أَن يَأْتِينَ بِفَاحِشَةٍ مُّبَيِّنَةٍ ۚ وَتِلْكَ حُدُودُ اللَّهِ ۚ وَمَن يَتَعَدَّ حُدُودَ اللَّهِ فَقَدْ ظَلَمَ نَفْسَهُ ۚ لَا تَدْرِي لَعَلَّ اللَّهَ يُحْدِثُ بَعْدَ ذَٰلِكَ أَمْرًا
Iwo Anabi, nigba ti e ba fe ko awon obinrin sile, e ko won sile pelu sise onka ojo opo fun ikosile won. Ki e si so onka ojo opo. Ki e beru Allahu, Oluwa yin. E ma se mu won jade kuro ninu ile won, awon naa ko si gbodo jade afi ti won ba lo se ibaje t’o foju han. Iwonyen si ni awon enu-ala ti Allahu gbekale. Enikeni ti o ba tayo awon enu-ala ti Allahu gbekale, o kuku ti sabosi si emi ara re. Iwo ko si mo boya Allahu maa mu oro titun sele leyin iyen
2فَإِذَا بَلَغْنَ أَجَلَهُنَّ فَأَمْسِكُوهُنَّ بِمَعْرُوفٍ أَوْ فَارِقُوهُنَّ بِمَعْرُوفٍ وَأَشْهِدُوا ذَوَيْ عَدْلٍ مِّنكُمْ وَأَقِيمُوا الشَّهَادَةَ لِلَّهِ ۚ ذَٰلِكُمْ يُوعَظُ بِهِ مَن كَانَ يُؤْمِنُ بِاللَّهِ وَالْيَوْمِ الْآخِرِ ۚ وَمَن يَتَّقِ اللَّهَ يَجْعَل لَّهُ مَخْرَجًا
Nigba ti won ba fe pari onka ojo opo won, e mu won modo ni ona t’o dara tabi ki e ko won sile ni ona t’o dara. E fi awon onideede meji ninu yin jerii si i. Ki e si gbe ijerii naa duro ni titori ti Allahu. Iyen ni A n fi se waasi fun enikeni ti o ba ni igbagbo ododo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin. Enikeni ti o ba n beru Allahu, O maa fun un ni ona abayo (ninu isoro)
3وَيَرْزُقْهُ مِنْ حَيْثُ لَا يَحْتَسِبُ ۚ وَمَن يَتَوَكَّلْ عَلَى اللَّهِ فَهُوَ حَسْبُهُ ۚ إِنَّ اللَّهَ بَالِغُ أَمْرِهِ ۚ قَدْ جَعَلَ اللَّهُ لِكُلِّ شَيْءٍ قَدْرًا
O si maa pese fun un ni aye ti ko ti rokan. Ati pe enikeni ti o ba gbekele Allahu, O maa to o. Dajudaju Allahu yoo mu oro Re de opin. Dajudaju Allahu ti ko odiwon akoko fun gbogbo nnkan
At-TalaqAtokọ Kurani
12Ẹsẹ
MedinanRevelation
1Ẹsẹ

Itumọ — At-Talaq 1

Surah At-Talaq Ẹsẹ 1 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Iwo Anabi, nigba ti e ba fe ko awon obinrin…

Surah Ẹsẹ 1/12 — Surah At-Talaq الطلاق (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Talaq Gbọ, Surah At-Talaq Itumọ, Surah At-Talaq mp3, Surah At-Talaq pdf. Ẹsẹ 1–3. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers