6 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮀﮁﮂﮃﮄ
114:1 So pe: "Mo sa di Oluwa awon eniyan
ﮅﮆﮇ
114:2 Oba awon eniyan
ﮈﮉﮊ
114:3 Olohun awon eniyan
ﮋﮌﮍﮎﮏ
114:4 nibi aburu (Esu) oniroyiroyi, olusaseyin (fun eni t’o ba daruko Allah)
ﮐﮑﮒﮓﮔﮕ
114:5 (Esu ni) eni ti o n ko royiroyi sinu awon okan eniyan
ﮖﮗﮘﮙ
114:6 (Esu naa) wa ninu alujannu ati eniyan

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers