PDF —
7 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Fatihah pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Fatihah pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Fatihah Itumọ. Surah Al-Fatihah (Meccan) 7 Ẹsẹ.

Surah Al-Fatihah Al-Baqarah →


7 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
ﭑﭒﭓﭔﭕ
1:1 Ni oruko Allahu, Ajoke-aye, Asake-orun
ﭖﭗﭘﭙﭚ
1:2 Gbogbo ope n je ti Allahu, Oluwa gbogbo eda
ﭛﭜﭝ
1:3 Ajoke-aye, Asake-orun
ﭞﭟﭠﭡ
1:4 Olukapa-ojo-esan
ﭢﭣﭤﭥﭦ
1:5 Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si
ﭧﭨﭩﭪ
1:6 Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa
ﭫﭬﭭﭮﭯﭰﭱﭲﭳﭴ
1:7 ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara)

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers