45 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭑﭒﭓﭔﭕ
50:1 Ƙof. (Allahu fi) al-Ƙur’an alapon-onle bura
ﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞﭟﭠﭡ
50:2 Sugbon won seemo nitori pe olukilo kan wa ba won lati aarin ara won. Awon alaigbagbo si wi pe: "Eyi ni ohun iyanu
ﭢﭣﭤﭥﭦﭧﭨﭩﭪ
50:3 Se nigba ti a ba ti ku, ti a ti di erupe (ni a oo tun ji dide pada). Iyen ni idapada to jinna (si nnkan ti o le sele)
ﭫﭬﭭﭮﭯﭰﭱﭲﭳﭴﭵ
50:4 Dajudaju A ti mo ohun ti ile n mu je ninu won. Tira (ise eda ) ti won n so si wa ni odo Wa
ﭶﭷﭸﭹﭺﭻﭼﭽﭾﭿ
50:5 Sibesibe won pe ododo (al-Ƙur’an) ni iro nigba ti o de ba won. Nitori naa, won ti wa ninu idaamu
ﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆﮇﮈﮉﮊﮋﮌ
50:6 Se won ko wo sanmo oke won bi A ti se mo on pa ati (bi) A ti se e ni oso, ti ko si si alafo sisan kan lara re
ﮍﮎﮏﮐﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗﮘ
50:7 Ati pe ile, A te e perese. A si ju awon apata t’o duro gbagidi sinu re. A si mu orisirisi irugbin t’o dara hu jade lati inu re
ﮙﮚﮛﮜﮝﮞ
50:8 (O je) ariwoye ati iranti fun gbogbo erusin to n seri pada (sibi ododo)
ﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧﮨﮩ
50:9 A n so omi ibukun kale lati sanmo. A si n fi mu awon ogba oko ati awon eso ti won maa kaje hu jade
ﮪﮫﮬﮭﮮﮯ
50:10 (A tun mu) igi dabinu hu ga, ti awon eso ori re so jigbinni
ﮰﮱﯓﯔﯕﯖﯗﯘﯙﯚﯛ
50:11 Arisiki ni fun awon eru (Allahu). A si n fi so oku ile di aye. Bayen ni ijade eda (lati inu saree yo se ri)
ﯜﯝﯞﯟﯠﯡﯢﯣ
50:12 Awon eniyan (Anabi) Nuh, awon eniyan Rass ati awon (eniyan) Thamud pe ododo niro siwaju won
ﯤﯥﯦﯧﯨ
50:13 Ati awon ‘Ad, Fir‘aon ati awon omo iya (Anabi) Lut
ﯩﯪﯫﯬﯭﯮﯯﯰﯱﯲﯳ
50:14 ati awon ara ’Aekah ati awon ijo Tubba‘u; gbogbo won pe awon Ojise ni opuro. Nitori naa, ileri Mi si di eto (lori won)
ﯴﯵﯶﯷﯸﯹﯺﯻﯼﯽﯾﯿ
50:15 Nje iseda akoko ko agara ba Wa bi? Rara, won wa ninu iyemeji nipa iseda (won) ni titun ni
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞﭟﭠ
50:16 Dajudaju A seda eniyan. A si mo ohun ti emi re n so fun un. Awa si sunmo on ju isan orun re
ﭡﭢﭣﭤﭥﭦﭧﭨﭩ
50:17 (Ranti) nigba ti (molaika) awon agboro-sile meji ba beresi gba oro (sile), ti okan jokoo si otun, ti okan jokoo si osi
ﭪﭫﭬﭭﭮﭯﭰﭱﭲ
50:18 (Eni kan) ko si nii so oro kan ayafi ki eso kan wa pelu re (fun akosile re)
ﭳﭴﭵﭶﭷﭸﭹﭺﭻﭼﭽ
50:19 Ati pe ipokaka iku yoo de lati fi ododo orun rinle. Iyen ni ohun ti iwo n sa fun
ﭾﭿﮀﮁﮂﮃﮄﮅ
50:20 Won a fon fere oniwo fun ajinde. Iyen ni ojo ileri naa
ﮆﮇﮈﮉﮊﮋﮌ
50:21 Emi kookan yoo wa pelu oludari kan ati elerii kan (ninu awon molaika)
ﮍﮎﮏﮐﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗﮘﮙ
50:22 Dajudaju iwo ti wa ninu igbagbera nibi eyi. A si ti si ebibo (oju) re kuro fun o bayii. Nitori naa, iriran re yoo riran kedere ni oni
ﮚﮛﮜﮝﮞﮟﮠ
50:23 (Molaika) alabaarin re yoo so pe: "Eyi ni ohun ti n be ni odo mi (gege bi akosile ise re)
ﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧ
50:24 E ju u sinu ina Jahanamo, gbogbo alaigbagbo olorikunkun
ﮨﮩﮪﮫﮬ
50:25 oludena-ise rere, alakoyo, oniyemeji
ﮭﮮﮯﮰﮱﯓﯔﯕﯖﯗﯘ
50:26 eni to mu olohun miiran mo Allahu. E ju u sinu iya lile
ﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡﯢﯣﯤ
50:27 (Esu) alabaarin re yoo wi pe: "Oluwa wa, emi ko ni mo si i lona, sugbon o ti wa ninu isina to jinna (si ododo) teletele
ﯥﯦﯧﯨﯩﯪﯫﯬﯭ
50:28 (Allahu) yoo so pe: "E ma se sariyanjiyan lodo Mi. Mo kuku ti se ileri fun yin siwaju
ﯮﯯﯰﯱﯲﯳﯴﯵﯶ
50:29 Won ko si le yi oro naa pada ni odo Mi. Emi ko si nii se abosi si awon eru Mi
ﯷﯸﯹﯺﯻﯼﯽﯾﯿﰀ
50:30 (Ranti) ojo ti A oo so fun ina Jahnamo pe: Sebi o ti kun?" O si maa so pe: "Sebi afikun tun wa
ﰁﰂﰃﰄﰅﰆ
50:31 Won maa sun Ogba Idera mo awon oluberu (Allahu). Ko si nii jinna (si won)
ﰇﰈﰉﰊﰋﰌﰍ
50:32 Eyi ni ohun ti A n se ni adehun fun gbogbo oluronupiwada, oluso (ofin Allahu)
ﰎﰏﰐﰑﰒﰓﰔﰕ
50:33 Enikeni ti o ba paya Allahu ni ikoko, ti o tun de pelu okan to seri pada si odo Allahu (nipa ironupiwada)
ﰖﰗﰘﰙﰚﰛﰜ
50:34 (A oo so fun won pe:) "E wo inu (Ogba Idera) pelu alaafia. Iyen ni ojo gbere
ﰝﰞﰟﰠﰡﰢﰣ
50:35 Ohun ti won n fe wa ninu re. Alekun si tun wa ni odo Wa
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞﭟﭠ
50:36 Meloo meloo ninu awon ijo ti A ti pare siwaju won. Won si ni agbara ju won lo. (Nigba ti iya de) won sa asala kiri ninu ilu. Nje ibusasi kan wa (fun won bi)
ﭡﭢﭣﭤﭥﭦﭧﭨﭩﭪﭫﭬﭭﭮ
50:37 Dajudaju iranti wa ninu iyen fun eni to ni okan tabi eni to fi eti sile, to wa nibe (pelu okan re)
ﭯﭰﭱﭲﭳﭴﭵﭶﭷﭸﭹﭺﭻﭼ
50:38 Dajudaju A seda awon sanmo, ile ati nnkan to wa laaarin awon mejeeji fun ojo mefa. Ko si re Wa rara (ambosibosi pe A oo sinmi ni ojo keje)
ﭽﭾﭿﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆﮇﮈﮉ
50:39 Nitori naa, se suuru lori ohun ti won n wi. Ki o si se afomo pelu idupe fun Oluwa Re siwaju yiyo oorun ati wiwo (re)
ﮊﮋﮌﮍﮎﮏ
50:40 Ati pe ni oru ati ni eyin irun se afomo fun Un
ﮐﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗ
50:41 Ki o si teti si ojo ti olupepe yoo pepe lati aye kan t’o sunmo
ﮘﮙﮚﮛﮜﮝﮞﮟﮠ
50:42 Ojo ti won yoo gbo igbe pelu ododo. Iyen ni ojo ijade eda (lati inu saree)
ﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧ
50:43 Dajudaju Awa, Awa l’A n so eda di alaaye. A si n so o di oku. Odo Wa si ni abo eda
ﮨﮩﮪﮫﮬﮭﮮﮯﮰﮱﯓ
50:44 (Ranti) ojo ti ile yoo faya perepere mo won lara, (ti won yoo maa) yara (jade lati inu ile). Iyen ni akojo t’o rorun fun Wa
ﯔﯕﯖﯗﯘﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡﯢﯣ
50:45 Awa nimo julo nipa ohun ti won n wi. Iwo ko si nii je won nipa (lati gbagbo). Nitori naa, fi al-Ƙur’an se iranti fun eni ti n paya ileri Mi

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers