Surah Al-A'la
PDF —
Built right in your browser — download starts automatically
Surah Al-A'la pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah Al-A'la pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-A'la Itumọ. Al-A'la (Meccan) 19 Ẹsẹ.
Related
- Al-A'la ItumọYorùbá
- Al-A'la mp3Gbọ
- Quran Index Yorùbá114
More Surah PDF
Surah Al-A'la

ﮟﮠﮡﮢﮣ
Safomo fun oruko Oluwa re, Eni giga julo
ﮤﮥﮦﮧ
Eni ti O da eda. O si se (orikee-rikee re) ni dogbadogba
ﮨﮩﮪﮫ
Eni ti O yan kadara (fun eda). O si to o sona
ﮬﮭﮮﮯ
Eni ti O mu koriko tutu (hu) jade
ﮰﮱﯓﯔ
O si so o di gbigbe t’o dudu
ﯕﯖﯗﯘ
Awa yoo maa ke (al-Ƙur’an) fun o. Iwo ko si nii gbagbe
ﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡﯢﯣ
Ayafi ohun ti Allahu ba fe. Dajudaju O mo gbangba ati ohun t’o pamo
ﯤﯥﯦ
Awa yo si se ise rere ni irorun fun o
ﯧﯨﯩﯪﯫ
Nitori naa, seranti ni aye ti iranti ti wulo
ﯬﯭﯮﯯ
Eni ti o maa paya (Allahu) maa lo iranti
ﭑﭒﭓ
Olori-buruku si maa takete si i
ﭔﭕﭖﭗﭘ
(Oun si ni) eni ti o maa wo inu Ina t’o tobi
ﭙﭚﭛﭜﭝﭞﭟ
Leyin naa, ko nii ku sinu re, ko si nii semi (alaafia)
ﭠﭡﭢﭣﭤ
Dajudaju eni ti o ba safomo (okan re) ti jere
ﭥﭦﭧﭨﭩ
O tun ranti oruko Oluwa re, o si kirun
ﭪﭫﭬﭭﭮ
Rara, nse l’e n gbe ajulo fun isemi aye
ﭯﭰﭱﭲ
Orun si loore julo, o si maa wa titi laelae
ﭳﭴﭵﭶﭷﭸ
Dajudaju eyi wa ninu awon takada akoko
ﭹﭺﭻﭼ
takada (Anabi) ’Ibrohim ati (Anabi) Musa
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







