PDF —
78 Ẹsẹ Medinan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Ar-Rahman pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Ar-Rahman pdf Yorùbá — Gbà Surah Ar-Rahman Itumọ. Surah Ar-Rahman (Medinan) 78 Ẹsẹ.



78 Ẹsẹ · Medinan · Yorùbá
bismillah
ﭷﭸ
55:1 Ajoke-aye
ﭹﭺﭻ
55:2 O fi imo al-Ƙur’an mo (eni ti O fe)
ﭼﭽﭾ
55:3 O seda eniyan
ﭿﮀﮁ
55:4 O si fi alaye (oro siso) mo on
ﮂﮃﮄﮅ
55:5 Oorun ati osupa (n rin) fun isiro (ojo aye)
ﮆﮇﮈﮉ
55:6 Awon itakun ile ati igi n fori kanle (fun Allahu)
ﮊﮋﮌﮍﮎ
55:7 Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon ofin deede lele (fun eda)
ﮏﮐﮑﮒﮓ
55:8 pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon
ﮔﮕﮖﮗﮘﮙﮚ
55:9 E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
ﮛﮜﮝﮞ
55:10 Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
ﮟﮠﮡﮢﮣﮤ
55:11 Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)
ﮥﮦﮧﮨﮩ
55:12 Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
ﮪﮫﮬﮭﮮ
55:13 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮯﮰﮱﯓﯔﯕ
55:14 (Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
ﯖﯗﯘﯙﯚﯛﯜ
55:15 O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
ﯝﯞﯟﯠﯡ
55:16 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯢﯣﯤﯥﯦ
55:17 Oluwa ibuyo oorun mejeeji ati ibuwo oorun mejeeji
ﯧﯨﯩﯪﯫ
55:18 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭑﭒﭓﭔ
55:19 (Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
ﭕﭖﭗﭘﭙ
55:20 Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)
ﭚﭛﭜﭝﭞ
55:21 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭟﭠﭡﭢﭣ
55:22 Okuta oniyebiye ati ileke iyun n jade ninu awon (odo) mejeeji naa
ﭤﭥﭦﭧﭨ
55:23 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭩﭪﭫﭬﭭﭮﭯ
55:24 Ti (Allahu) ni awon oko oju-omi gogoro t’o n rin ninu agbami odo (ti won da) bi apata giga
ﭰﭱﭲﭳﭴ
55:25 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭵﭶﭷﭸﭹ
55:26 Gbogbo eni t’o wa lori ile maa tan
ﭺﭻﭼﭽﭾﭿﮀ
55:27 Oju Oluwa re, Atobi, Alapon-onle si maa wa titi laelae
ﮁﮂﮃﮄﮅ
55:28 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮆﮇﮈﮉﮊﮋﮌﮍﮎﮏﮐﮑ
55:29 Awon t’o wa ninu awon sanmo ati ile n beere (nnkan) lodo Re; O si wa lori ise lojoojumo
ﮒﮓﮔﮕﮖ
55:30 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮗﮘﮙﮚﮛ
55:31 A oo mu tiyin gbo (lojo esan), eyin eniyan ati alujannu
ﮜﮝﮞﮟﮠ
55:32 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧﮨﮩﮪﮫﮬﮭﮮﮯﮰﮱﯓ
55:33 Eyin awujo alujannu ati eniyan, ti e ba lagbara lati sa jade ninu awon agbegbe sanmo ati ile, e sa jade. E o le sa jade afi pelu agbara
ﯔﯕﯖﯗﯘ
55:34 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡ
55:35 Won maa ju eta-para ina ati eta-para ide le eyin mejeeji lori, eyin mejeeji ko si le ran’ra yin lowo
ﯢﯣﯤﯥﯦ
55:36 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯧﯨﯩﯪﯫﯬﯭ
55:37 Nitori naa, nigba ti sanmo ba faya perepere, o si maa pon wa we bi epo pupa
ﯮﯯﯰﯱﯲ
55:38 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯳﯴﯵﯶﯷﯸﯹﯺﯻ
55:39 Nitori naa, ni ojo yen Won o nii bi eniyan ati alujannu kan leere nipa ese re; (o ti wa ni akosile ni odo Wa)
ﯼﯽﯾﯿﰀ
55:40 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﰁﰂﰃﰄﰅﰆﰇ
55:41 Won maa mo awon elese pelu ami ara won. Won si maa fi aaso ori ati ese gba won mu
ﭑﭒﭓﭔﭕ
55:42 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜ
55:43 Eyi ni ina Jahanamo ti awon elese n pe niro
ﭝﭞﭟﭠﭡﭢ
55:44 Won yoo maa rin lo rin bo laaarin Ina ati omi t’o gbona pari
ﭣﭤﭥﭦﭧ
55:45 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭨﭩﭪﭫﭬﭭ
55:46 Ogba Idera meji n be fun eni t’o ba paya iduro re niwaju Oluwa re
ﭮﭯﭰﭱﭲ
55:47 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭳﭴﭵ
55:48 (Awon Ogba Idera mejeeji ni) awon eka igi gigun
ﭶﭷﭸﭹﭺ
55:49 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭻﭼﭽﭾ
55:50 Odo meji t’o n san wa ninu ogba mejeeji
ﭿﮀﮁﮂﮃ
55:51 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮄﮅﮆﮇﮈﮉ
55:52 Orisi meji meji ni eso kookan t’o wa ninu ogba mejeeji
ﮊﮋﮌﮍﮎ
55:53 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮏﮐﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗﮘﮙ
55:54 Won yoo rogboku lori ite, ti awon ite inu re je aran t’o nipon. Awon eso ogba mejeeji si wa ni arowoto
ﮚﮛﮜﮝﮞ
55:55 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧﮨ
55:56 Awon obinrin ti ki i wo okunrin miiran wa ninu Ogba Idera. Eniyan ati alujannu kan ko si fowo kan won ri siwaju won
ﮩﮪﮫﮬﮭ
55:57 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﮮﮯﮰﮱ
55:58 Won da bii ileke segi ati ileke iyun
ﯓﯔﯕﯖﯗ
55:59 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯘﯙﯚﯛﯜﯝ
55:60 Nje esan miiran wa fun sise rere bi ko se (esan) rere
ﯞﯟﯠﯡﯢ
55:61 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯣﯤﯥﯦ
55:62 Ogba meji kan tun n be yato si meji (akoko yen)
ﯧﯨﯩﯪﯫ
55:63 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯬﯭ
55:64 Alawo eweko (ni Ogba mejeeji naa)
ﯮﯯﯰﯱﯲ
55:65 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯳﯴﯵﯶ
55:66 Awon odo meji t’o n tu omi jade lai dawo duro wa (ninu ogba mejeeji naa)
ﯷﯸﯹﯺﯻ
55:67 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﯼﯽﯾﯿﰀ
55:68 Eso ipanu, dabinu ati eso rumon wa ninu ogba mejeeji
ﰁﰂﰃﰄﰅ
55:69 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭑﭒﭓﭔ
55:70 Awon obinrin rere, arewa wa ninu awon Ogba Idera
ﭕﭖﭗﭘﭙ
55:71 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭚﭛﭜﭝﭞ
55:72 Awon eleyinju-ege kan (ni won), ti A fi pamo sinu ile-oso
ﭟﭠﭡﭢﭣ
55:73 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭤﭥﭦﭧﭨﭩﭪ
55:74 Eniyan ati alujannu kan ko fowo kan won ri siwaju won
ﭫﭬﭭﭮﭯ
55:75 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭰﭱﭲﭳﭴﭵﭶ
55:76 Won yoo rogboku lori awon timutimu alawo eweko ati ite t’o dara
ﭷﭸﭹﭺﭻ
55:77 Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
ﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂ
55:78 Ibukun ni fun oruko Oluwa re, Atobi, Alapon-onle

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers