PDF —
25 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Inshiqaq pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Inshiqaq pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Inshiqaq Itumọ. Surah Al-Inshiqaq (Meccan) 25 Ẹsẹ.



25 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭣﭤﭥﭦ
84:1 Nigba ti sanmo ba faya perepere
ﭧﭨﭩﭪ
84:2 o gbo, o si tele ase Oluwa re ni. O si di dandan fun un lati se bee –
ﭫﭬﭭﭮ
84:3 ati nigba ti A ba fe ile loju
ﭯﭰﭱﭲﭳ
84:4 o maa ju ohun ti o wa ninu re sita, o si maa pa sofo
ﭴﭵﭶﭷ
84:5 – o gbo, o si tele ase Oluwa re ni. O si di dandan fun un lati se bee – (ni ojo yen ni eda maa ri ise owo re)
ﭸﭹﭺﭻﭼﭽﭾﭿﮀ
84:6 Iwo eniyan dajudaju iwo n se ise karakara ni ise asepade Oluwa re. O si maa mu un pade Re
ﮁﮂﮃﮄﮅﮆ
84:7 Nitori naa, ni ti eni ti won ba fun ni iwe ise re ni owo otun re
ﮇﮈﮉﮊﮋ
84:8 laipe A maa se isiro-ise (re) ni isiro irorun
ﮌﮍﮎﮏﮐ
84:9 O si maa pada si odo awon eniyan re (ninu Ogba Idera) leni idunnu
ﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗ
84:10 Ni ti eni ti won ba si fun ni iwe ise re lati eyin re
ﮘﮙﮚﮛ
84:11 laipe o maa kigbe iparun
ﮜﮝﮞ
84:12 O si maa wo inu Ina t’o n jo fofo
ﮟﮠﮡﮢﮣﮤ
84:13 Dajudaju o ti wa laaarin awon eniyan re leni idunnu (si aigbagbo nile aye)
ﮥﮦﮧﮨﮩﮪ
84:14 Dajudaju o lero pe oun ko nii pada (si odo Allahu ni)
ﮫﮬﮭﮮﮯﮰﮱﯓ
84:15 Rara (o maa pada). Dajudaju Oluwa re je Oluriran nipa re
ﯔﯕﯖﯗ
84:16 Nitori naa, Emi (Allahu) n bura pelu awonpapa
ﯘﯙﯚﯛ
84:17 Mo tun bura pelu oru ati ohun ti o ko jo sinu re
ﯜﯝﯞﯟ
84:18 Mo tun bura pelu osupa nigba ti o ba degba (pelu imole re)
ﯠﯡﯢﯣﯤ
84:19 Dajudaju eyin yoo maa bo sinu wahala kan lati inu wahala kan
ﯥﯦﯧﯨﯩ
84:20 Ki l’o se won na ti won ko fi gbagbo ni ododo
ﯪﯫﯬﯭﯮﯯﯰﯱ
84:21 Nigba ti won ba si ke al-Ƙur’an fun won, won ko nii fori kanle
ﯲﯳﯴﯵﯶ
84:22 Rara, nse ni awon t’o sai gbagbo n pe e niro
ﯷﯸﯹﯺﯻ
84:23 Allahu si nimo julo nipa ohun ti won n fi pamo (sinu okan won)
ﯼﯽﯾﯿ
84:24 Nitori naa, fun won ni iro iya eleta-elero
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚ
84:25 Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, esan ti ko nii pin n be fun won

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers