7 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭦﭧﭨﭩﭪ
107:1 So fun mi nipa eni t’o n pe Ojo Esan niro
ﭫﭬﭭﭮﭯ
107:2 Iyen ni eni t’o n le omo-orukan danu
ﭰﭱﭲﭳﭴﭵ
107:3 Ko si nii gbiyanju lati bo mekunnu
ﭶﭷﭸ
107:4 Egbe ni fun awon (munaafiki) t’o n kirun; ko tumo si “ohun t’o n run eniyan”. Amo itumo “irun” ni “ohun t’o n run ese olukirun” nitori pe ti olukirun ba ti se aluwala ni o ti san gbogbo awon ese weere ti o ti fi awon orikee ara re se siwaju. Bakan naa
ﭹﭺﭻﭼﭽﭾ
107:5 awon t’o n gbagbe lati kirun won ni asiko re
ﭿﮀﮁﮂ
107:6 awon t’o n se sekarimi
ﮃﮄﮅ
107:7 ati pe won n hanna ohun elo (fun awon eniyan)

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers