PDF —
28 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Jinn pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Jinn pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Jinn Itumọ. Surah Al-Jinn (Meccan) 28 Ẹsẹ.



28 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞ
72:1 So pe: "Won fi imisi ranse si mi pe dajudaju ijo kan ninu awon alujannu teti (si al-Ƙur’an)." Won si so pe: "Dajudaju awa gbo al-Ƙur’an iyanu
ﭟﭠﭡﭢﭣﭤﭥﭦﭧﭨﭩ
72:2 O n setosona sibi imona. Nitori naa, a gba a gbo. Awa ko si nii fi eni kan kan se akegbe fun Oluwa wa
ﭪﭫﭬﭭﭮﭯﭰﭱﭲﭳ
72:3 Ati pe dajudaju titobi Oluwa wa ga. Ko fi eni kan kan se aya ati omo
ﭴﭵﭶﭷﭸﭹﭺﭻ
72:4 Dajudaju omugo ninu wa maa n so isokuso nipa Allahu
ﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆ
72:5 Dajudaju awa si n ro pe eniyan ati alujannu ko nii pa iro mo Allahu ni
ﮇﮈﮉﮊﮋﮌﮍﮎﮏﮐﮑﮒ
72:6 Ati pe dajudaju awon okunrin kan ninu eniyan maa n fi awon okunrin kan ninu awon alujannu wa aabo. Awon alujannu si se alekun aburu fun won
ﮓﮔﮕﮖﮗﮘﮙﮚﮛﮜ
72:7 Dajudaju awon alujannu lero gege bi eyin eniyan naa se lero pe Allahu ko nii gbe eni kan kan dide (leyin iku)
ﮝﮞﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥ
72:8 Dajudaju awa wa (oro ayogbo) wa si sanmo, a si ba a ti o ti kun fun awon eso t’o lagbara ati awon ogunna
ﮦﮧﮨﮩﮪﮫﮬﮭﮮﮯﮰﮱﯓﯔ
72:9 Dajudaju awa maa n jokoo sibe ni awon ibudo kan fun gbigbo oro. Sugbon eni t’o ba joro gbo lasiko yii, o maa ri ogunna t’o ti lugo de e
ﯕﯖﯗﯘﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡﯢ
72:10 Dajudaju awa ko si mo boya aburu ni won gba lero pelu awon t’o wa lori ile tabi Oluwa won gbero imona fun won
ﯣﯤﯥﯦﯧﯨﯩﯪﯫﯬﯭ
72:11 Dajudaju awon eni rere wa ninu wa. Awon miiran yato si iyen tun wa ninu wa. A wa loju ona (esin) otooto
ﯮﯯﯰﯱﯲﯳﯴﯵﯶﯷﯸﯹ
72:12 Dajudaju awa mo amodaju pe awa ko le mori bo mo Allahu lowo lori ile. Awa ko si le sa mo On lowo
ﯺﯻﯼﯽﯾﯿﰀﰁﰂﰃﰄﰅﰆﰇﰈﰉ
72:13 Dajudaju nigba ti a gbo nipa imona (lati inu al-Ƙur’an), a gba a gbo. Nitori naa, enikeni ti o ba gba Oluwa re gbo, ki o ma beru adinku (esan rere) ati (alekun) aburu
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚﭛﭜ
72:14 Dajudaju awon musulumi wa ninu wa. Awon arufin naa wa ninu wa. Nitori naa, enikeni ti o ba se ’Islam, awon wonyen ni won se awari imona
ﭝﭞﭟﭠﭡﭢ
72:15 Ni ti awon arufin, awon ni won maa je igi ikona fun ina Jahanamo.”
ﭣﭤﭥﭦﭧﭨﭩﭪ
72:16 Ati pe ti o ba je pe won duro sinsin loju ona (’Islam) ni, dajudaju Awa iba fun won ni omi pupo mu
ﭫﭬﭭﭮﭯﭰﭱﭲﭳﭴﭵﭶ
72:17 Nitori ki A le fi dan won wo ni. Enikeni ti o ba gbunri kuro nibi iranti Oluwa re, O maa mu un wo inu iya inira
ﭷﭸﭹﭺﭻﭼﭽﭾﭿ
72:18 Dajudaju awon mosalasi n je ti Allahu. Nitori naa, e o gbodo fi pe eni kan pelu Allahu
ﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆﮇﮈﮉﮊ
72:19 Dajudaju nigba ti erusin Allahu dide duro t’o n pe Allahu, awon alujannu fee maa difun-un-unfun lodo re (lati teti si al-Ƙur’an)
ﮋﮌﮍﮎﮏﮐﮑﮒﮓ
72:20 So pe: "Oluwa mi ni mo n pe. Ati pe emi ko nii so eni kan kan di akegbe fun Un
ﮔﮕﮖﮗﮘﮙﮚﮛﮜ
72:21 So pe: "Dajudaju emi ko ni ikapa lori inira ati imona fun yin
ﮝﮞﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥﮦﮧﮨﮩ
72:22 So pe: "Dajudaju emi, ko si eni kan t’o le gba mi la lodo Allahu. Emi ko si ri ibusasi kan leyin Re
ﮪﮫﮬﮭﮮﮯﮰﮱﯓﯔﯕﯖﯗﯘﯙﯚﯛﯜ
72:23 Afi (ki ng se) ikede (t’o wa) lati odo Allahu ati awon ise Re (t’O fi ran mi). Enikeni t’o ba yapa Allahu ati Ojise Re, dajudaju ina Jahanamo n be fun un. Olusegbere ni won ninu re titi laelae
ﯝﯞﯟﯠﯡﯢﯣﯤﯥﯦﯧﯨ
72:24 (Alaigbagbo ko nii ye sai gbagbo) titi di igba ti won yoo fi ri ohun ti A n se ni adehun fun won. Nigba naa, won yoo mo ta ni o le julo ni alaranse, ti o si kere julo ni onka
ﯩﯪﯫﯬﯭﯮﯯﯰﯱﯲﯳﯴ
72:25 So pe: "Emi ko mo boya ohun ti Won n se ni adehun fun yin ti sunmo tabi Oluwa mi yoo fun un ni akoko (t’o jinna)
ﯵﯶﯷﯸﯹﯺﯻﯼ
72:26 Onimo-ikoko, ko si fi (imo) ikoko Re han eni kan
ﯽﯾﯿﰀﰁﰂﰃﰄﰅﰆﰇﰈﰉﰊ
72:27 ayafi eni ti O salesa t’o je Ojise. Dajudaju O n mu eso kan rin niwaju Ojise naa ati leyin re
ﰋﰌﰍﰎﰏﰐﰑﰒﰓﰔﰕﰖﰗﰘ
72:28 nitori ki O le safi han pe won ti je awon ise Oluwa won. Ati pe Allahu fi imo rokiri ka ohun ti n be lodo won. O si so onka gbogbo nnkan

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers