Fussilat · 53/54
Itumọ Aṣẹ ohun — Fussilat
سَنُرِيهِمْ آيَاتِنَا فِي الْآفَاقِ وَفِي أَنفُسِهِمْ حَتَّىٰ يَتَبَيَّنَ لَهُمْ أَنَّهُ الْحَقُّ ۗ أَوَلَمْ يَكْفِ بِرَبِّكَ أَنَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ شَهِيدٌ ۝٥٣
Sanureehim Aayaatinaa fil aafaaqi wa feee anfusihim hattaa yatabaiyana lahum annahul haqq; awa lam yakfi bi Rabbika annahoo `alaa kulli shai-in Shaheed
📖 Ni Yorùbá
A oo maa fi awon ami Wa han won ninu ofurufu ati ninu emi ara won titi o maa fi han kedere si won pe dajudaju al-Ƙur’an ni ododo. Nje Oluwa re ko to ki o je pe dajudaju Oun ni Arinu-rode lori gbogbo nnkan

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 51-54 — Fussilat

51وَإِذَا أَنْعَمْنَا عَلَى الْإِنسَانِ أَعْرَضَ وَنَأَىٰ بِجَانِبِهِ وَإِذَا مَسَّهُ الشَّرُّ فَذُو دُعَاءٍ عَرِيضٍ
Ati pe nigba ti A ba se idera fun eniyan, o maa gbunri (kuro ni odo Wa). O si maa segberaga. Nigba ti aburu ba si fowo ba a, nigba naa l’o maa di aladuaa regede
52قُلْ أَرَأَيْتُمْ إِن كَانَ مِنْ عِندِ اللَّهِ ثُمَّ كَفَرْتُم بِهِ مَنْ أَضَلُّ مِمَّنْ هُوَ فِي شِقَاقٍ بَعِيدٍ
So pe: " E so fun mi, ti o ba je pe al-Ƙur’an wa lati odo Allahu, leyin naa ti e sai gbagbo ninu re (se eyin ko ti wa ninu iyapa bi?)" Ta l’o sina ju eni ti o wa ninu iyapa t’o jinna (si ododo)
53سَنُرِيهِمْ آيَاتِنَا فِي الْآفَاقِ وَفِي أَنفُسِهِمْ حَتَّىٰ يَتَبَيَّنَ لَهُمْ أَنَّهُ الْحَقُّ ۗ أَوَلَمْ يَكْفِ بِرَبِّكَ أَنَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ شَهِيدٌ
A oo maa fi awon ami Wa han won ninu ofurufu ati ninu emi ara won titi o maa fi han kedere si won pe dajudaju al-Ƙur’an ni ododo. Nje Oluwa re ko to ki o je pe dajudaju Oun ni Arinu-rode lori gbogbo nnkan
54أَلَا إِنَّهُمْ فِي مِرْيَةٍ مِّن لِّقَاءِ رَبِّهِمْ ۗ أَلَا إِنَّهُ بِكُلِّ شَيْءٍ مُّحِيطٌ
Gbo, dajudaju won wa ninu iyemeji nipa ipade Oluwa won. Gbo, dajudaju Allahu yi gbogbo nnkan ka
FussilatAtokọ Kurani
54Ẹsẹ
MeccanRevelation
53Ẹsẹ

Itumọ — Fussilat 53

Surah Fussilat Ẹsẹ 53 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : A oo maa fi awon ami Wa han won ninu…

Surah Ẹsẹ 53/54 — Fussilat فصلت (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Fussilat Gbọ, Fussilat Itumọ, Fussilat mp3, Fussilat pdf. Ẹsẹ 51–54. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers