PDF —
19 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-'Alaq pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-'Alaq pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-'Alaq Itumọ. Surah Al-'Alaq (Meccan) 19 Ẹsẹ.

← At-TinSurah Al-'Alaq Al-Qadr →


19 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮕﮖﮗﮘﮙﮚ
96:1 Ke (al-Ƙur’an) pelu oruko Oluwa re, Eni ti O da eda
ﮛﮜﮝﮞﮟ
96:2 O seda eniyan lati ara eje didi
ﮠﮡﮢﮣ
96:3 Ke e. Oluwa re ni Alapon-onle julo
ﮤﮥﮦﮧ
96:4 Eni ti O fi imo nipa gege ikowe mo eniyan
ﮨﮩﮪﮫﮬﮭ
96:5 O fi imo ti eniyan ko mo mo on
ﮮﮯﮰﮱﯓ
96:6 Ni ti ododo, dajudaju eniyan kuku n tayo enu-ala
ﯔﯕﯖﯗ
96:7 nitori pe o rira re ni oloro
ﯘﯙﯚﯛﯜ
96:8 Dajudaju odo Oluwa re ni abo eda
ﯝﯞﯟﯠ
96:9 So fun mi nipa eni t’o n ko
ﯡﯢﯣﯤ
96:10 fun erusin kan nigba ti (erusin naa) kirun
ﯥﯦﯧﯨﯩﯪ
96:11 So fun mi (nipa esan re) ti o ba je pe o wa lori imona (’Islam)
ﯫﯬﯭﯮ
96:12 tabi pe o pase iberu (Allahu)
ﭑﭒﭓﭔﭕ
96:13 So fun mi (nipa iya re) ti o ba je pe o pe ododo niro, ti o si keyin si i
ﭖﭗﭘﭙﭚﭛ
96:14 Se ko mo pe dajudaju Allahu n ri (oun ni)
ﭜﭝﭞﭟﭠﭡﭢ
96:15 Bee ni (Allahu n ri i.) Dajudaju ti ko ba jawo (nibi didi i lowo), dajudaju A maa fi aaso ori re wo o (sinu Ina)
ﭣﭤﭥﭦ
96:16 aaso ori opuro, elese
ﭧﭨﭩ
96:17 Nitori naa, ki o pe awon olubajokoo re
ﭪﭫﭬ
96:18 Awa maa pe awon molaika eso Ina
ﭭﭮﭯﭰﭱﭲﭳ
96:19 Rara o, ma se tele tire. Fori kanle (ki o kirun), ki o sunmo (Allahu)

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers