Al-Qalam · 41/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
أَمْ لَهُمْ شُرَكَاءُ فَلْيَأْتُوا بِشُرَكَائِهِمْ إِن كَانُوا صَادِقِينَ ۝٤١
Am lahum shurakaaa`u falyaatoo bishurakaaa `ihim in kaanoo saadiqeen
📖 Ni Yorùbá
Tabi won ni awon orisa kan? Ki won mu awon orisa won wa nigba naa ti won ba je olododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 39-43 — Surah Al-Qalam

39أَمْ لَكُمْ أَيْمَانٌ عَلَيْنَا بَالِغَةٌ إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۙ إِنَّ لَكُمْ لَمَا تَحْكُمُونَ
Nje e ni awon adehun kan lodo wa ti o maa wa titi di Ojo Ajinde pe: "Dajudaju tiyin ni idajo ti e ba ti mu wa
40سَلْهُمْ أَيُّهُم بِذَٰلِكَ زَعِيمٌ
Bi won leere wo pe ewo ninu won l’o le fowo iyen soya
41أَمْ لَهُمْ شُرَكَاءُ فَلْيَأْتُوا بِشُرَكَائِهِمْ إِن كَانُوا صَادِقِينَ
Tabi won ni awon orisa kan? Ki won mu awon orisa won wa nigba naa ti won ba je olododo
42يَوْمَ يُكْشَفُ عَن سَاقٍ وَيُدْعَوْنَ إِلَى السُّجُودِ فَلَا يَسْتَطِيعُونَ
Ni ojo ti A maa si ojugun sile, A si maa pe won sibi iforikanle, won ko si nii le se e
43خَاشِعَةً أَبْصَارُهُمْ تَرْهَقُهُمْ ذِلَّةٌ ۖ وَقَدْ كَانُوا يُدْعَوْنَ إِلَى السُّجُودِ وَهُمْ سَالِمُونَ
Oju won yoo wale. Iyepere maa bo won mole. Won kuku ti pe won sibi iforikanle nigba ti won ni alaafia (won ko si kirun)
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
41Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 41

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 41 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Tabi won ni awon orisa kan? Ki won mu awon…

Surah Ẹsẹ 41/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 39–43. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers