Al-Qalam · 40/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
سَلْهُمْ أَيُّهُم بِذَٰلِكَ زَعِيمٌ ۝٤٠
Salhum ayyuhum bizaa lika za`eem
📖 Ni Yorùbá
Bi won leere wo pe ewo ninu won l’o le fowo iyen soya

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 38-42 — Surah Al-Qalam

38إِنَّ لَكُمْ فِيهِ لَمَا تَخَيَّرُونَ
pe dajudaju eyin le ni ohun ti e ba n sa lesa ninu idajo
39أَمْ لَكُمْ أَيْمَانٌ عَلَيْنَا بَالِغَةٌ إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۙ إِنَّ لَكُمْ لَمَا تَحْكُمُونَ
Nje e ni awon adehun kan lodo wa ti o maa wa titi di Ojo Ajinde pe: "Dajudaju tiyin ni idajo ti e ba ti mu wa
40سَلْهُمْ أَيُّهُم بِذَٰلِكَ زَعِيمٌ
Bi won leere wo pe ewo ninu won l’o le fowo iyen soya
41أَمْ لَهُمْ شُرَكَاءُ فَلْيَأْتُوا بِشُرَكَائِهِمْ إِن كَانُوا صَادِقِينَ
Tabi won ni awon orisa kan? Ki won mu awon orisa won wa nigba naa ti won ba je olododo
42يَوْمَ يُكْشَفُ عَن سَاقٍ وَيُدْعَوْنَ إِلَى السُّجُودِ فَلَا يَسْتَطِيعُونَ
Ni ojo ti A maa si ojugun sile, A si maa pe won sibi iforikanle, won ko si nii le se e
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
40Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 40

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 40 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Bi won leere wo pe ewo ninu won l’o le…

Surah Ẹsẹ 40/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 38–42. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers