Ibrahim · 37/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Ibrahim
رَّبَّنَا إِنِّي أَسْكَنتُ مِن ذُرِّيَّتِي بِوَادٍ غَيْرِ ذِي زَرْعٍ عِندَ بَيْتِكَ الْمُحَرَّمِ رَبَّنَا لِيُقِيمُوا الصَّلَاةَ فَاجْعَلْ أَفْئِدَةً مِّنَ النَّاسِ تَهْوِي إِلَيْهِمْ وَارْزُقْهُم مِّنَ الثَّمَرَاتِ لَعَلَّهُمْ يَشْكُرُونَ ۝٣٧
Rabbanaaa inneee askantu min zurriyyatee biwaadin ghairi zee zar`in `inda Baitikal Muharrami Rabbanaa liyuqeemus Salaata faj`al af`idatam minan naasi tahweee ilaihim warzuqhum minas samaraati la`allahum yashkuroon
📖 Ni Yorùbá
Oluwa wa, dajudaju emi wa ibugbe fun aromodomo mi si ile afonifoji, ile ti ko ni eso, nitosi Ile Re Olowo. Oluwa wa, nitori ki won le kirun ni. Nitori naa, je ki okan awon eniyan fa sodo won. Ki O si pese awon eso fun won nitori ki won le dupe (fun O)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 35-39 — Ibrahim

35وَإِذْ قَالَ إِبْرَاهِيمُ رَبِّ اجْعَلْ هَٰذَا الْبَلَدَ آمِنًا وَاجْنُبْنِي وَبَنِيَّ أَن نَّعْبُدَ الْأَصْنَامَ
(Ranti) nigba ti (Anabi) ’Ibrohim so pe: "Oluwa mi, se ilu yii ni ilu ifayabale. Ki O si mu emi ati awon omo mi jinna si jijosin fun awon orisa
36رَبِّ إِنَّهُنَّ أَضْلَلْنَ كَثِيرًا مِّنَ النَّاسِ ۖ فَمَن تَبِعَنِي فَإِنَّهُ مِنِّي ۖ وَمَنْ عَصَانِي فَإِنَّكَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Oluwa mi, dajudaju awon orisa ti ko opolopo ninu awon eniyan sonu. Nitori naa, enikeni ti o ba tele mi, dajudaju oun ni eni mi. Enikeni ti o ba si yapa mi, dajudaju Iwo ni Alaforijin, Asake
37رَّبَّنَا إِنِّي أَسْكَنتُ مِن ذُرِّيَّتِي بِوَادٍ غَيْرِ ذِي زَرْعٍ عِندَ بَيْتِكَ الْمُحَرَّمِ رَبَّنَا لِيُقِيمُوا الصَّلَاةَ فَاجْعَلْ أَفْئِدَةً مِّنَ النَّاسِ تَهْوِي إِلَيْهِمْ وَارْزُقْهُم مِّنَ الثَّمَرَاتِ لَعَلَّهُمْ يَشْكُرُونَ
Oluwa wa, dajudaju emi wa ibugbe fun aromodomo mi si ile afonifoji, ile ti ko ni eso, nitosi Ile Re Olowo. Oluwa wa, nitori ki won le kirun ni. Nitori naa, je ki okan awon eniyan fa sodo won. Ki O si pese awon eso fun won nitori ki won le dupe (fun O)
38رَبَّنَا إِنَّكَ تَعْلَمُ مَا نُخْفِي وَمَا نُعْلِنُ ۗ وَمَا يَخْفَىٰ عَلَى اللَّهِ مِن شَيْءٍ فِي الْأَرْضِ وَلَا فِي السَّمَاءِ
Oluwa wa, dajudaju Iwo l’O mo ohun ti a n fi pamo ati ohun ti a n se afihan re. Ko si si kini kan ninu ile ati ninu sanmo t’o pamo fun Allahu
39الْحَمْدُ لِلَّهِ الَّذِي وَهَبَ لِي عَلَى الْكِبَرِ إِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ ۚ إِنَّ رَبِّي لَسَمِيعُ الدُّعَاءِ
Gbogbo ope n je ti Allahu, Eni ti O fun mi ni ’Ismo‘il ati ’Ishaƙ nigba ti mo ti darugbo. Dajudaju, Oluwa mi ni Olugbo adua
IbrahimAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
37Ẹsẹ

Itumọ — Ibrahim 37

Surah Ibrahim Ẹsẹ 37 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Oluwa wa, dajudaju emi wa ibugbe fun aromodomo mi si…

Surah Ẹsẹ 37/52 — Ibrahim إبراهيم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Ibrahim Gbọ, Ibrahim Itumọ, Ibrahim mp3, Ibrahim pdf. Ẹsẹ 35–39. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers