Al-Furqan · 52/77
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Furqan
فَلَا تُطِعِ الْكَافِرِينَ وَجَاهِدْهُم بِهِ جِهَادًا كَبِيرًا ٥٢
Transliteration
Falaa tuti`il kaafireena wa jaahidhum bihee jihaadan kabeeraa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Nitori naa, ma se tele awon alaigbagbo. Ki o si fi (al-Ƙur’an) ja won ni ogun t’o tobi
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 50-54 — Surah Al-Furqan
50وَلَقَدْ صَرَّفْنَاهُ بَيْنَهُمْ لِيَذَّكَّرُوا فَأَبَىٰ أَكْثَرُ النَّاسِ إِلَّا كُفُورًا
Dajudaju A ti pin omi yii laaarin won nitori ki won le ranti (ike Oluwa won). Sugbon opolopo eniyan ko (lati ranti) afi aimoore
51وَلَوْ شِئْنَا لَبَعَثْنَا فِي كُلِّ قَرْيَةٍ نَّذِيرًا
Ti o ba je pe A ba fe ni, A iba gbe olukilo kan dide ninu ilu kookan
52فَلَا تُطِعِ الْكَافِرِينَ وَجَاهِدْهُم بِهِ جِهَادًا كَبِيرًا
Nitori naa, ma se tele awon alaigbagbo. Ki o si fi (al-Ƙur’an) ja won ni ogun t’o tobi
53۞ وَهُوَ الَّذِي مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ هَٰذَا عَذْبٌ فُرَاتٌ وَهَٰذَا مِلْحٌ أُجَاجٌ وَجَعَلَ بَيْنَهُمَا بَرْزَخًا وَحِجْرًا مَّحْجُورًا
Oun ni Eni ti O mu awon odo meji san kiri. Eyi (ni omi) t’o dun gan-an. Eyi si (ni omi) iyo t’o moro. O fi gaga si aarin awon mejeeji. (O si) se e ni eewo ponnbele (fun won lati ko inira ba eda)
54وَهُوَ الَّذِي خَلَقَ مِنَ الْمَاءِ بَشَرًا فَجَعَلَهُ نَسَبًا وَصِهْرًا ۗ وَكَانَ رَبُّكَ قَدِيرًا
Oun ni Eni ti O seda abara lati inu omi. O se ibatan ebi ati ibatan ana fun un, Oluwa re si n je Alagbara
Al-FurqanAtokọ Kurani
77Ẹsẹ
MeccanRevelation
52Ẹsẹ
Itumọ — Al-Furqan 52
Surah Al-Furqan Ẹsẹ 52 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori naa, ma se tele awon alaigbagbo. Ki o si…Surah Ẹsẹ 52/77 — Surah Al-Furqan الفرقان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Furqan Gbọ, Surah Al-Furqan Itumọ, Surah Al-Furqan mp3, Surah Al-Furqan pdf. Ẹsẹ 50–54. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








