Al-Mujadilah · 22/22
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Mujadilah
لَّا تَجِدُ قَوْمًا يُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ وَالْيَوْمِ الْآخِرِ يُوَادُّونَ مَنْ حَادَّ اللَّهَ وَرَسُولَهُ وَلَوْ كَانُوا آبَاءَهُمْ أَوْ أَبْنَاءَهُمْ أَوْ إِخْوَانَهُمْ أَوْ عَشِيرَتَهُمْ ۚ أُولَٰئِكَ كَتَبَ فِي قُلُوبِهِمُ الْإِيمَانَ وَأَيَّدَهُم بِرُوحٍ مِّنْهُ ۖ وَيُدْخِلُهُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُمْ وَرَضُوا عَنْهُ ۚ أُولَٰئِكَ حِزْبُ اللَّهِ ۚ أَلَا إِنَّ حِزْبَ اللَّهِ هُمُ الْمُفْلِحُونَ ۝٢٢
Laa tajidu qawmany yu`minoona billaahi wal yawmil aakhiri yuwaaaddoona man haaaddal laaha wa Rasoolahoo wa law kaanooo aabaaa`ahum aw abnaaa`ahum aw ikhwaa nahum aw `asheeratahum; ulaaa`ika kataba fee quloobihi mul eemaana wa ayyadahum biroohimminhu wa yudkhilu hum jannatin tajree min tahtihal anhaaru khaalideena feehaa; radiyal laahu `anhum wa radoo `anh; ulaaa `ika hizbul laah; alaaa inna hizbal laahi humul muflihoon
📖 Ni Yorùbá
O o nii ri ijo kan t’o gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin, ki won maa nifee awon t’o ba yapa Allahu ati Ojise Re koda ki won je awon baba won, tabi awon omo won tabi awon arakunrin won tabi awon ibatan won. Awon wonyen ni Allahu ti ko igbagbo ododo sinu okan won. Allahu si kun won lowo pelu imole (al-Ƙur’an ati isegun) lati odo Re. O si maa mu won wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Allahu yonu si won. Won si yonu si (ohun ti Allahu fun won). Awon wonyen ni ijo Allahu. Gbo! Dajudaju ijo Allahu, awon ni olujere

🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 20-22 — Al-Mujadilah

20إِنَّ الَّذِينَ يُحَادُّونَ اللَّهَ وَرَسُولَهُ أُولَٰئِكَ فِي الْأَذَلِّينَ
Dajudaju awon t’o n yapa Allahu ati Ojise Re, awon wonyen wa ninu awon oluyepere julo
21كَتَبَ اللَّهُ لَأَغْلِبَنَّ أَنَا وَرُسُلِي ۚ إِنَّ اللَّهَ قَوِيٌّ عَزِيزٌ
Allahu ko o pe: "Dajudaju Mo maa bori; Emi ati awon Ojise Mi." Dajudaju Allahu ni Alagbara, Olubori
22لَّا تَجِدُ قَوْمًا يُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ وَالْيَوْمِ الْآخِرِ يُوَادُّونَ مَنْ حَادَّ اللَّهَ وَرَسُولَهُ وَلَوْ كَانُوا آبَاءَهُمْ أَوْ أَبْنَاءَهُمْ أَوْ إِخْوَانَهُمْ أَوْ عَشِيرَتَهُمْ ۚ أُولَٰئِكَ كَتَبَ فِي قُلُوبِهِمُ الْإِيمَانَ وَأَيَّدَهُم بِرُوحٍ مِّنْهُ ۖ وَيُدْخِلُهُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُمْ وَرَضُوا عَنْهُ ۚ أُولَٰئِكَ حِزْبُ اللَّهِ ۚ أَلَا إِنَّ حِزْبَ اللَّهِ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
O o nii ri ijo kan t’o gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin, ki won maa nifee awon t’o ba yapa Allahu ati Ojise Re koda ki won je awon baba won, tabi awon omo won tabi awon arakunrin won tabi awon ibatan won. Awon wonyen ni Allahu ti ko igbagbo ododo sinu okan won. Allahu si kun won lowo pelu imole (al-Ƙur’an ati isegun) lati odo Re. O si maa mu won wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Allahu yonu si won. Won si yonu si (ohun ti Allahu fun won). Awon wonyen ni ijo Allahu. Gbo! Dajudaju ijo Allahu, awon ni olujere
Al-MujadilahAtokọ Kurani
22Ẹsẹ
MedinanRevelation
22Ẹsẹ

Itumọ — Al-Mujadilah 22

Surah Al-Mujadilah Ẹsẹ 22 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : O o nii ri ijo kan t’o gbagbo ninu Allahu…

Surah Ẹsẹ 22/22 — Al-Mujadilah المجادلة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Mujadilah Gbọ, Al-Mujadilah Itumọ, Al-Mujadilah mp3, Al-Mujadilah pdf. Ẹsẹ 20–22. Ni Yorùbá: العربية.

Al-Kur'an

Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers