Al-Anfal · 24/75
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anfal
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اسْتَجِيبُوا لِلَّهِ وَلِلرَّسُولِ إِذَا دَعَاكُمْ لِمَا يُحْيِيكُمْ ۖ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ يَحُولُ بَيْنَ الْمَرْءِ وَقَلْبِهِ وَأَنَّهُ إِلَيْهِ تُحْشَرُونَ ٢٤
Transliteration
Yaaa aiyuhal lazeena aamanus tajeeboo lillaahi wa lir Rasooli izaa da`aakum limaa yuhyeekum wa`lamooo annal laaha yahoolu bainal mar`i wa qalbihee wa anahooo ilaihi tuhsharoon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e jepe ti Allahu ati ti Ojise, nigba ti o ba pe yin sibi nnkan ti o maa mu yin semi. Ki e si mo pe dajudaju Allahu n sediwo laaarin eniyan ati okan re. Dajudaju odo Re si ni won maa ko yin jo si
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 22-26 — Al-Anfal
22۞ إِنَّ شَرَّ الدَّوَابِّ عِندَ اللَّهِ الصُّمُّ الْبُكْمُ الَّذِينَ لَا يَعْقِلُونَ
Dajudaju eda abemi t’o buru julo ni odo Allahu ni awon aditi, ayaya ti ko se laakaye
23وَلَوْ عَلِمَ اللَّهُ فِيهِمْ خَيْرًا لَّأَسْمَعَهُمْ ۖ وَلَوْ أَسْمَعَهُمْ لَتَوَلَّوا وَّهُم مُّعْرِضُونَ
Ti o ba je pe Allahu mo oore kan lara won ni, iba je ki won gbo. Ti (Allahu) ba si fun won gbo ni, dajudaju won maa peyin da, won yo si maa gbunri
24يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اسْتَجِيبُوا لِلَّهِ وَلِلرَّسُولِ إِذَا دَعَاكُمْ لِمَا يُحْيِيكُمْ ۖ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ يَحُولُ بَيْنَ الْمَرْءِ وَقَلْبِهِ وَأَنَّهُ إِلَيْهِ تُحْشَرُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e jepe ti Allahu ati ti Ojise, nigba ti o ba pe yin sibi nnkan ti o maa mu yin semi. Ki e si mo pe dajudaju Allahu n sediwo laaarin eniyan ati okan re. Dajudaju odo Re si ni won maa ko yin jo si
25وَاتَّقُوا فِتْنَةً لَّا تُصِيبَنَّ الَّذِينَ ظَلَمُوا مِنكُمْ خَاصَّةً ۖ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ شَدِيدُ الْعِقَابِ
E sora fun adanwo kan ti ko nii mo lori awon t’o sabosi ninu yin nikan. Ki e si mo pe dajudaju Allahu le nibi iya
26وَاذْكُرُوا إِذْ أَنتُمْ قَلِيلٌ مُّسْتَضْعَفُونَ فِي الْأَرْضِ تَخَافُونَ أَن يَتَخَطَّفَكُمُ النَّاسُ فَآوَاكُمْ وَأَيَّدَكُم بِنَصْرِهِ وَرَزَقَكُم مِّنَ الطَّيِّبَاتِ لَعَلَّكُمْ تَشْكُرُونَ
E ranti pe nigba ti eyin kere, ti won n foju tinrin yin lori ile, ti e si n paya pe awon eniyan maa ji yin gbe lo, nigba naa (Allahu) se ibugbe fun yin (ninu ilu Modinah Onimoole), O si fi aranse Re se ikunlowo fun yin. O tun pese fun yin ninu awon nnkan daadaa nitori ki e le dupe
Al-AnfalAtokọ Kurani
75Ẹsẹ
MedinanRevelation
24Ẹsẹ
Itumọ — Al-Anfal 24
Surah Al-Anfal Ẹsẹ 24 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ti e gbagbo ni ododo, e jepe ti Allahu…Surah Ẹsẹ 24/75 — Al-Anfal الأنفال (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anfal Gbọ, Al-Anfal Itumọ, Al-Anfal mp3, Al-Anfal pdf. Ẹsẹ 22–26. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








