Al-Baqarah · 182/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
فَمَنْ خَافَ مِن مُّوصٍ جَنَفًا أَوْ إِثْمًا فَأَصْلَحَ بَيْنَهُمْ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ ۚ إِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ ۝١٨٢
Faman khaafa mim moosin janafan aw isman fa aslaha bainahum falaaa ismaa `alayh; innal laaha Ghafooru Raheem
📖 Ni Yorùbá
Sugbon eni ti o ba beru asise tabi iwa ese lati odo eni ti o so asoole, ti o si se atunse laaarin (awon ti ogun to si). Nitori naa, ko si ese fun un. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 180-184 — Surah Al-Baqarah

180كُتِبَ عَلَيْكُمْ إِذَا حَضَرَ أَحَدَكُمُ الْمَوْتُ إِن تَرَكَ خَيْرًا الْوَصِيَّةُ لِلْوَالِدَيْنِ وَالْأَقْرَبِينَ بِالْمَعْرُوفِ ۖ حَقًّا عَلَى الْمُتَّقِينَ
A se e ni oran-anyan fun yin, nigba ti iku ba de ba eni kan ninu yin, ti o si fi dukia sile, pe ki o so asoole ni ona t’o dara fun awon obi mejeeji ati awon ebi. (Eyi je) ojuse fun awon oluberu (Allahu)
181فَمَن بَدَّلَهُ بَعْدَمَا سَمِعَهُ فَإِنَّمَا إِثْمُهُ عَلَى الَّذِينَ يُبَدِّلُونَهُ ۚ إِنَّ اللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
Enikeni ti o ba yi i pada leyin ti o ti gbo o, ese re yo si wa lorun awon t’o n yi i pada. Dajudaju Allahu ni Olugbo, Onimo
182فَمَنْ خَافَ مِن مُّوصٍ جَنَفًا أَوْ إِثْمًا فَأَصْلَحَ بَيْنَهُمْ فَلَا إِثْمَ عَلَيْهِ ۚ إِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
Sugbon eni ti o ba beru asise tabi iwa ese lati odo eni ti o so asoole, ti o si se atunse laaarin (awon ti ogun to si). Nitori naa, ko si ese fun un. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
183يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا كُتِبَ عَلَيْكُمُ الصِّيَامُ كَمَا كُتِبَ عَلَى الَّذِينَ مِن قَبْلِكُمْ لَعَلَّكُمْ تَتَّقُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, A se aawe naa ni oran-anyan fun yin, gege bi A ti se e ni oran-anyan fun awon t’o siwaju yin, nitori ki e le beru (Allahu)
184أَيَّامًا مَّعْدُودَاتٍ ۚ فَمَن كَانَ مِنكُم مَّرِيضًا أَوْ عَلَىٰ سَفَرٍ فَعِدَّةٌ مِّنْ أَيَّامٍ أُخَرَ ۚ وَعَلَى الَّذِينَ يُطِيقُونَهُ فِدْيَةٌ طَعَامُ مِسْكِينٍ ۖ فَمَن تَطَوَّعَ خَيْرًا فَهُوَ خَيْرٌ لَّهُ ۚ وَأَن تَصُومُوا خَيْرٌ لَّكُمْ ۖ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ
(E gba aawe naa) fun awon ojo ti o ni onka. (Sugbon) enikeni ninu yin ti o ba je alaisan, tabi o wa lori irin-ajo, (o maa san) onka (gbese aawe re) ni awon ojo miiran. Ati pe itanran (iyen) fifun mekunnu ni ounje l’o di dandan fun awon t’o maa fi inira gba aawe. Enikeni ti o ba finnufindo se (alekun) ise oloore, o kuku loore julo fun un. Ati pe ki e gba aawe loore julo fun yin ti e ba mo
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
182Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 182

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 182 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Sugbon eni ti o ba beru asise tabi iwa ese…

Surah Ẹsẹ 182/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 180–184. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers