An-Naml · 8/93
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Naml
فَلَمَّا جَاءَهَا نُودِيَ أَن بُورِكَ مَن فِي النَّارِ وَمَنْ حَوْلَهَا وَسُبْحَانَ اللَّهِ رَبِّ الْعَالَمِينَ ۝٨
Falammaa jaaa`ahaa noodiya am boorika man finnnnaari wa man hawlahaa wa Subhaanal laahi Rabbil `aalameen
📖 Ni Yorùbá
Nigba ti o de ibe, A pepe pe ki ibukun maa be fun eni ti o wa nibi ina naa ati eni ti o wa ni ayika re. Mimo si ni fun Allahu, Oluwa gbogbo eda
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 6-10 — An-Naml

6وَإِنَّكَ لَتُلَقَّى الْقُرْآنَ مِن لَّدُنْ حَكِيمٍ عَلِيمٍ
Dajudaju o n gba al-Ƙur’an lati odo Ologbon, Onimo
7إِذْ قَالَ مُوسَىٰ لِأَهْلِهِ إِنِّي آنَسْتُ نَارًا سَآتِيكُم مِّنْهَا بِخَبَرٍ أَوْ آتِيكُم بِشِهَابٍ قَبَسٍ لَّعَلَّكُمْ تَصْطَلُونَ
(Ranti) nigba ti (Anabi) Musa so fun awon eniyan re pe: “Dajudaju mo ri ina kan. Mo si maa lo mu iro kan wa fun yin lati ibe, tabi ki ng mu ogunna kan t’o n tanna wa fun yin nitori ki e le yena
8فَلَمَّا جَاءَهَا نُودِيَ أَن بُورِكَ مَن فِي النَّارِ وَمَنْ حَوْلَهَا وَسُبْحَانَ اللَّهِ رَبِّ الْعَالَمِينَ
Nigba ti o de ibe, A pepe pe ki ibukun maa be fun eni ti o wa nibi ina naa ati eni ti o wa ni ayika re. Mimo si ni fun Allahu, Oluwa gbogbo eda
9يَا مُوسَىٰ إِنَّهُ أَنَا اللَّهُ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Musa, dajudaju Emi ni Allahu, Alagbara, Ologbon
10وَأَلْقِ عَصَاكَ ۚ فَلَمَّا رَآهَا تَهْتَزُّ كَأَنَّهَا جَانٌّ وَلَّىٰ مُدْبِرًا وَلَمْ يُعَقِّبْ ۚ يَا مُوسَىٰ لَا تَخَفْ إِنِّي لَا يَخَافُ لَدَيَّ الْمُرْسَلُونَ
Ju opa re sile. (O si se bee.) Amo nigba ti o ri i t’o n yira pada bi eni pe ejo ni, Musa peyin da, o n sa lo. Ko si pada. (Allahu so pe:) Musa, ma se paya. Dajudaju awon Ojise ki i paya lodo Mi
An-NamlAtokọ Kurani
93Ẹsẹ
MeccanRevelation
8Ẹsẹ

Itumọ — An-Naml 8

Surah An-Naml Ẹsẹ 8 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba ti o de ibe, A pepe pe ki ibukun…

Surah Ẹsẹ 8/93 — An-Naml النمل (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Naml Gbọ, An-Naml Itumọ, An-Naml mp3, An-Naml pdf. Ẹsẹ 6–10. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers