At-Taghabun · 4/18
Itumọ Aṣẹ ohun — At-Taghabun
يَعۡلَمُ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَيَعۡلَمُ مَا تُسِرُّونَ وَمَا تُعۡلِنُونَۚ وَٱللَّهُ عَلِيمُۢ بِذَاتِ ٱلصُّدُورِ  ۝٤
Ya`lamu maa fis samaawaati wal ardi wa ya`lamu maa tusirroona wa maa tu`linoon; wallaahu `Aleemum bizaatis sudoor
📖 Ni Yorùbá
O mo ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ile. O si mo ohun ti e n fi pamo ati ohun ti e n safi han re. Allahu si ni Onimo nipa ohun t’o wa ninu igba-aya eda
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 2-6 — At-Taghabun

2هُوَ ٱلَّذِي خَلَقَكُمۡ فَمِنكُمۡ كَافِرٌ وَمِنكُم مُّؤۡمِنٌۚ وَٱللَّهُ بِمَا تَعۡمَلُونَ بَصِيرٌ 
Oun ni Eni ti O seda yin. Alaigbagbo wa ninu yin. Onigbagbo ododo si wa ninu yin. Allahu si ni Oluriran nipa ohun ti e n se
3خَلَقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَ بِٱلۡحَقِّ وَصَوَّرَكُمۡ فَأَحۡسَنَ صُوَرَكُمۡۖ وَإِلَيۡهِ ٱلۡمَصِيرُ 
O seda awon sanmo ati ile pelu ododo. O ya aworan yin. O si se awon aworan yin daradara. Odo Re si ni abo eda
4يَعۡلَمُ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَيَعۡلَمُ مَا تُسِرُّونَ وَمَا تُعۡلِنُونَۚ وَٱللَّهُ عَلِيمُۢ بِذَاتِ ٱلصُّدُورِ 
O mo ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ile. O si mo ohun ti e n fi pamo ati ohun ti e n safi han re. Allahu si ni Onimo nipa ohun t’o wa ninu igba-aya eda
5أَلَمۡ يَأۡتِكُمۡ نَبَؤُاْ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ مِن قَبۡلُ فَذَاقُواْ وَبَالَ أَمۡرِهِمۡ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمٌ 
Se iro awon t’o sai gbagbo ni isaaju ko ti i de ba yin ni? Nitori naa, won to iya oran won wo. Iya eleta-elero si wa fun won
6ذَٰلِكَ بِأَنَّهُۥ كَانَت تَّأۡتِيهِمۡ رُسُلُهُم بِٱلۡبَيِّنَٰتِ فَقَالُوٓاْ أَبَشَرٌ يَهۡدُونَنَا فَكَفَرُواْ وَتَوَلَّواْۖ وَّٱسۡتَغۡنَى ٱللَّهُۚ وَٱللَّهُ غَنِيٌّ حَمِيدٌ 
Iyen nitori pe dajudaju awon Ojise won n wa ba won pelu awon eri t’o yanju. Won si wi pe: "Se abara l’o maa fi ona mo wa?" Nitori naa, won sai gbagbo. Won si peyin da (si ododo). Allahu si roro lai si awon. Ati pe Allahu ni Oloro, Olope
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
4Ẹsẹ

Itumọ — At-Taghabun 4

Surah Ẹsẹ 4/18 — At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: At-Taghabun Gbọ, At-Taghabun Itumọ, At-Taghabun mp3, At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 2–6. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers