Surah Al-Humazah pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah Al-Humazah pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Humazah Itumọ. Surah Al-Humazah (Meccan) 9 Ẹsẹ.
Related
More Surah PDF
Surah Al-Humazah

ﭢﭣﭤﭥﭦ
104:1
Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni
ﭧﭨﭩﭪﭫ
104:2
eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin)
ﭬﭭﭮﭯﭰ
104:3
O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye)
ﭱﭲﭳﭴﭵﭶ
104:4
Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni
ﭷﭸﭹﭺﭻ
104:5
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh
ﭼﭽﭾﭿ
104:6
(Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere)
ﮀﮁﮂﮃﮄ
104:7
eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo
ﮅﮆﮇﮈ
104:8
Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata
ﮉﮊﮋﮌ
104:9
(Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina)
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







