8 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮣﮤﮥ
102:1 Wiwa oore aye ni opolopo fun iyanran sise ti ko airoju fesin ba yin
ﮦﮧﮨﮩ
102:2 titi e fi wo inu saree
ﮪﮫﮬﮭ
102:3 Rara (ko ye ko ri bee, amo) laipe e maa mo
ﮮﮯﮰﮱﯓ
102:4 Leyin naa, ni ododo laipe e maa mo
ﯔﯕﯖﯗﯘﯙ
102:5 Bee ni, ti o ba je pe e ni imo amodaju ni (eyin iba ti se bee)
ﯚﯛﯜ
102:6 Dajudaju e maa ri ina Jehim
ﯝﯞﯟﯠﯡ
102:7 Leyin naa, dajudaju e maa ri i ni aridaju
ﯢﯣﯤﯥﯦﯧ
102:8 Leyin naa, dajudaju ni ojo yen won maa bi yin leere nipa igbadun (aye yii)

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers