PDF —
11 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Qari'ah pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Qari'ah pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Qari'ah Itumọ. Surah Al-Qari'ah (Meccan) 11 Ẹsẹ.



11 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭴﭵ
101:1 Akoko ijaya
ﭶﭷﭸ
101:2 Ki ni Akoko ijaya
ﭹﭺﭻﭼﭽ
101:3 Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya
ﭾﭿﮀﮁﮂﮃ
101:4 (Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita
ﮄﮅﮆﮇﮈ
101:5 awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu
ﮉﮊﮋﮌﮍ
101:6 Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won
ﮎﮏﮐﮑﮒ
101:7 o si maa wa ninu isemi t’o yonu si
ﮓﮔﮕﮖﮗ
101:8 Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye
ﮘﮙﮚ
101:9 Hawiyah si ni ibugbe re
ﮛﮜﮝﮞﮟ
101:10 Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee
ﮠﮡﮢ
101:11 (Ohun ni) Ina gbigbona gan-an

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers