Al-Anbiya · 80/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Anbiya
وَعَلَّمْنَاهُ صَنْعَةَ لَبُوسٍ لَّكُمْ لِتُحْصِنَكُم مِّن بَأْسِكُمْ ۖ فَهَلْ أَنتُمْ شَاكِرُونَ ۝٨٠
Wa `allamanaahu san`ata laboosil lakum lituhsinakum mim baasikum fahal antum shaakiroon
📖 Ni Yorùbá
A tun fun un ni imo nipa sise ewu irin fun yin nitori ki o le je odi iso fun yin nibi ogun yin. Nitori naa, nje oludupe (fun Allahu) ni eyin bi

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 78-82 — Surah Al-Anbiya

78وَدَاوُودَ وَسُلَيْمَانَ إِذْ يَحْكُمَانِ فِي الْحَرْثِ إِذْ نَفَشَتْ فِيهِ غَنَمُ الْقَوْمِ وَكُنَّا لِحُكْمِهِمْ شَاهِدِينَ
(E ranti Anabi) Dawud ati (Anabi) Sulaemon, nigba ti awon mejeeji n se idajo lori (oro) oko, nigba ti agutan ijo kan jeko wo inu oko naa. Awa si je Olujerii si idajo won
79فَفَهَّمْنَاهَا سُلَيْمَانَ ۚ وَكُلًّا آتَيْنَا حُكْمًا وَعِلْمًا ۚ وَسَخَّرْنَا مَعَ دَاوُودَ الْجِبَالَ يُسَبِّحْنَ وَالطَّيْرَ ۚ وَكُنَّا فَاعِلِينَ
A si fun (Anabi) Sulaemon ni agboye re. Ati pe ikookan (won) ni A fun ni ipo Anabi ati imo. A si te awon apata ati eye ba; won n se afomo (fun Allahu) pelu (Anabi) Dawud. Awa l’A se won bee
80وَعَلَّمْنَاهُ صَنْعَةَ لَبُوسٍ لَّكُمْ لِتُحْصِنَكُم مِّن بَأْسِكُمْ ۖ فَهَلْ أَنتُمْ شَاكِرُونَ
A tun fun un ni imo nipa sise ewu irin fun yin nitori ki o le je odi iso fun yin nibi ogun yin. Nitori naa, nje oludupe (fun Allahu) ni eyin bi
81وَلِسُلَيْمَانَ الرِّيحَ عَاصِفَةً تَجْرِي بِأَمْرِهِ إِلَى الْأَرْضِ الَّتِي بَارَكْنَا فِيهَا ۚ وَكُنَّا بِكُلِّ شَيْءٍ عَالِمِينَ
A si te ategun lile lori ba fun (Anabi) Sulaemon. O n gbe e lo pelu ase re sori ile ti A fi ibukun si. A si n je Onimo nipa gbogbo nnkan
82وَمِنَ الشَّيَاطِينِ مَن يَغُوصُونَ لَهُ وَيَعْمَلُونَ عَمَلًا دُونَ ذَٰلِكَ ۖ وَكُنَّا لَهُمْ حَافِظِينَ
Ninu awon esu, awon t’o n wa kusa okun tun wa fun un. Won tun n se ise miiran yato si iyen. Awa si n je Oluso fun won
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
80Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 80

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 80 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : A tun fun un ni imo nipa sise ewu irin…

Surah Ẹsẹ 80/112 — Surah Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Anbiya Gbọ, Surah Al-Anbiya Itumọ, Surah Al-Anbiya mp3, Surah Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 78–82. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers