Ash-Shu'ara · 4/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Ash-Shu'ara
إِن نَّشَأْ نُنَزِّلْ عَلَيْهِم مِّنَ السَّمَاءِ آيَةً فَظَلَّتْ أَعْنَاقُهُمْ لَهَا خَاضِعِينَ ۝٤
In nashaa nunazzil `alaihim minas samaaa`i Aayatan fazallat a`naaquhum lahaa khaadi`een
📖 Ni Yorùbá
Ti A ba fe, A maa so ami kan kale fun won lati sanmo. Awon orun won ko si nii ye teriba fun un
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 2-6 — Ash-Shu'ara

2تِلْكَ آيَاتُ الْكِتَابِ الْمُبِينِ
Iwonyi ni awon ayah Tira t’o n yanju oro eda
3لَعَلَّكَ بَاخِعٌ نَّفْسَكَ أَلَّا يَكُونُوا مُؤْمِنِينَ
Nitori ki ni o se maa para re pe won ko je onigbagbo ododo
4إِن نَّشَأْ نُنَزِّلْ عَلَيْهِم مِّنَ السَّمَاءِ آيَةً فَظَلَّتْ أَعْنَاقُهُمْ لَهَا خَاضِعِينَ
Ti A ba fe, A maa so ami kan kale fun won lati sanmo. Awon orun won ko si nii ye teriba fun un
5وَمَا يَأْتِيهِم مِّن ذِكْرٍ مِّنَ الرَّحْمَٰنِ مُحْدَثٍ إِلَّا كَانُوا عَنْهُ مُعْرِضِينَ
Ko si iranti kan ti o maa de ba won ni titun lati odo Ajoke-aye afi ki won je olugbunri kuro nibe
6فَقَدْ كَذَّبُوا فَسَيَأْتِيهِمْ أَنبَاءُ مَا كَانُوا بِهِ يَسْتَهْزِئُونَ
Dajudaju won ti pe (ayah Wa) niro. Nitori naa, awon iro ohun ti won n fi se yeye n bo wa ba won
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
4Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 4

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 4 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti A ba fe, A maa so ami kan kale…

Surah Ẹsẹ 4/227 — Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Ash-Shu'ara Gbọ, Ash-Shu'ara Itumọ, Ash-Shu'ara mp3, Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 2–6. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers