Aal-Imran · 134/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
الَّذِينَ يُنفِقُونَ فِي السَّرَّاءِ وَالضَّرَّاءِ وَالْكَاظِمِينَ الْغَيْظَ وَالْعَافِينَ عَنِ النَّاسِ ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ ۝١٣٤
Allazeena yunfiqoona fissarraaa`i waddarraaa`i wal kaazimeenal ghaiza wal aafeena `anin-naas; wallaahu yuhibbul muhsineen
📖 Ni Yorùbá
Awon t’o n na owo won nigba idera ati nigba inira, awon ti n gbe ibinu mi, awon alamojuukuro fun awon eniyan nibi asise; Allahu nifee awon oluse-rere

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 132-136 — Surah Aal-Imran

132وَأَطِيعُوا اللَّهَ وَالرَّسُولَ لَعَلَّكُمْ تُرْحَمُونَ
Ki e tele ti Allahu ati Ojise nitori ki A le ke yin
133۞ وَسَارِعُوا إِلَىٰ مَغْفِرَةٍ مِّن رَّبِّكُمْ وَجَنَّةٍ عَرْضُهَا السَّمَاوَاتُ وَالْأَرْضُ أُعِدَّتْ لِلْمُتَّقِينَ
E yara wa aforijin lodo Oluwa yin ati Ogba Idera kan, eyi ti ibu re to awon sanmo ati ile, ti Won pa lese sile fun awon oluberu (Allahu)
134الَّذِينَ يُنفِقُونَ فِي السَّرَّاءِ وَالضَّرَّاءِ وَالْكَاظِمِينَ الْغَيْظَ وَالْعَافِينَ عَنِ النَّاسِ ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ
Awon t’o n na owo won nigba idera ati nigba inira, awon ti n gbe ibinu mi, awon alamojuukuro fun awon eniyan nibi asise; Allahu nifee awon oluse-rere
135وَالَّذِينَ إِذَا فَعَلُوا فَاحِشَةً أَوْ ظَلَمُوا أَنفُسَهُمْ ذَكَرُوا اللَّهَ فَاسْتَغْفَرُوا لِذُنُوبِهِمْ وَمَن يَغْفِرُ الذُّنُوبَ إِلَّا اللَّهُ وَلَمْ يُصِرُّوا عَلَىٰ مَا فَعَلُوا وَهُمْ يَعْلَمُونَ
Awon ti (o je pe) nigba ti won ba se ibaje kan tabi ti won ba sabosi si emi ara won, won a ranti Allahu, won a si toro aforijin fun ese won, - Ta si ni O n fori awon ese jin (eda) bi ko se Allahu. Won ko si taku sori ohun ti won se nigba ti won mo (pe ese ni)
136أُولَٰئِكَ جَزَاؤُهُم مَّغْفِرَةٌ مِّن رَّبِّهِمْ وَجَنَّاتٌ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ وَنِعْمَ أَجْرُ الْعَامِلِينَ
Awon wonyen, esan won lodo Oluwa won ni aforijin ati awon Ogba Idera kan ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Esan oluse-ise rere si dara
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
134Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 134

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 134 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon t’o n na owo won nigba idera ati nigba…

Surah Ẹsẹ 134/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 132–136. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers