Al-Mujadilah · 16/22
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Mujadilah
اتَّخَذُوا أَيْمَانَهُمْ جُنَّةً فَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ فَلَهُمْ عَذَابٌ مُّهِينٌ ١٦
Transliteration
Ittakhazooo aymaanahum junnatan fasaddoo `an sabeelil laahi falahum `azaabum muheen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Won fi ibura won se aabo; won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu. Nitori naa, iya ti i yepere eda wa fun won
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 14-18 — Al-Mujadilah
14۞ أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ تَوَلَّوْا قَوْمًا غَضِبَ اللَّهُ عَلَيْهِم مَّا هُم مِّنكُمْ وَلَا مِنْهُمْ وَيَحْلِفُونَ عَلَى الْكَذِبِ وَهُمْ يَعْلَمُونَ
Se o o ri awon t’o mu ijo kan ti Allahu binu si ni ore? Won ki i se ara yin, won ko si je ara won. Won yo si maa bura lori iro, won si mo
15أَعَدَّ اللَّهُ لَهُمْ عَذَابًا شَدِيدًا ۖ إِنَّهُمْ سَاءَ مَا كَانُوا يَعْمَلُونَ
Allahu ti pese iya lile de won. Dajudaju ohun ti won n se nise buru
16اتَّخَذُوا أَيْمَانَهُمْ جُنَّةً فَصَدُّوا عَن سَبِيلِ اللَّهِ فَلَهُمْ عَذَابٌ مُّهِينٌ
Won fi ibura won se aabo; won si seri awon eniyan kuro loju ona (esin) Allahu. Nitori naa, iya ti i yepere eda wa fun won
17لَّن تُغْنِيَ عَنْهُمْ أَمْوَالُهُمْ وَلَا أَوْلَادُهُم مِّنَ اللَّهِ شَيْئًا ۚ أُولَٰئِكَ أَصْحَابُ النَّارِ ۖ هُمْ فِيهَا خَالِدُونَ
Awon dukia won ati awon omo won ko nii fi kini kan ro won loro ni odo Allahu. Awon wonyen ni ero inu Ina. Olusegbere si ni won ninu re
18يَوْمَ يَبْعَثُهُمُ اللَّهُ جَمِيعًا فَيَحْلِفُونَ لَهُ كَمَا يَحْلِفُونَ لَكُمْ ۖ وَيَحْسَبُونَ أَنَّهُمْ عَلَىٰ شَيْءٍ ۚ أَلَا إِنَّهُمْ هُمُ الْكَاذِبُونَ
Ni ojo ti Allahu yoo gbe gbogbo won dide patapata, won yo si maa bura fun Un gege bi won se n bura fun yin. Won n lero pe dajudaju awon ti ri nnkan se. Gbo! Dajudaju awon, awon ni opuro
Al-MujadilahAtokọ Kurani
22Ẹsẹ
MedinanRevelation
16Ẹsẹ
Itumọ — Al-Mujadilah 16
Surah Al-Mujadilah Ẹsẹ 16 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won fi ibura won se aabo; won si seri awon…Surah Ẹsẹ 16/22 — Al-Mujadilah المجادلة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Mujadilah Gbọ, Al-Mujadilah Itumọ, Al-Mujadilah mp3, Al-Mujadilah pdf. Ẹsẹ 14–18. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








