Al-Qalam · 32/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
عَسَىٰ رَبُّنَا أَن يُبْدِلَنَا خَيْرًا مِّنْهَا إِنَّا إِلَىٰ رَبِّنَا رَاغِبُونَ ۝٣٢
Asaa rabbunaaa any yubdilanaa khairam minhaaa innaaa ilaa rabbinaa raaghiboon
📖 Ni Yorùbá
O see se ki Oluwa wa fi eyi t’o dara ju eyi lo paaro re fun wa. Dajudaju odo Oluwa wa ni awa n rokan oore si
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 30-34 — Al-Qalam

30فَأَقْبَلَ بَعْضُهُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ يَتَلَاوَمُونَ
Apa kan won koju si apa kan; won si n dara won lebi
31قَالُوا يَا وَيْلَنَا إِنَّا كُنَّا طَاغِينَ
Won wi pe: "Egbe wa o! Dajudaju awa je olutayo-enu ala
32عَسَىٰ رَبُّنَا أَن يُبْدِلَنَا خَيْرًا مِّنْهَا إِنَّا إِلَىٰ رَبِّنَا رَاغِبُونَ
O see se ki Oluwa wa fi eyi t’o dara ju eyi lo paaro re fun wa. Dajudaju odo Oluwa wa ni awa n rokan oore si
33كَذَٰلِكَ الْعَذَابُ ۖ وَلَعَذَابُ الْآخِرَةِ أَكْبَرُ ۚ لَوْ كَانُوا يَعْلَمُونَ
Bayen ni iya naa se ri (fun won). Iya orun si tobi julo, ti o ba je pe won mo
34إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتِ النَّعِيمِ
Dajudaju awon Ogba Idera wa fun awon oluberu lodo Oluwa won
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
32Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 32

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 32 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : O see se ki Oluwa wa fi eyi t’o dara…

Surah Ẹsẹ 32/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 30–34. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers