Surah Al-Qari'ah ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Qari'ah pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (11 Ẹsẹ — مكية). Al-Qari'ah Gbọ, Al-Qari'ah Itumọ, Al-Qari'ah mp3, Al-Qari'ah pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Qari'ah

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
الْقَارِعَةُ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Akoko ijaya
مَا الْقَارِعَةُ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Ki ni Akoko ijaya
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْقَارِعَةُ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya
يَوْمَ يَكُونُ النَّاسُ كَالْفَرَاشِ الْمَبْثُوثِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
(Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita
وَتَكُونُ الْجِبَالُ كَالْعِهْنِ الْمَنفُوشِ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu
فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَازِينُهُ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won
فَهُوَ فِي عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
o si maa wa ninu isemi t’o yonu si
وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَازِينُهُ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye
فَأُمُّهُ هَاوِيَةٌ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
Hawiyah si ni ibugbe re
وَمَا أَدْرَاكَ مَا هِيَهْ ۝١٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 10
Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee
نَارٌ حَامِيَةٌ ۝١١
📖 Itumọ Ẹsẹ 11
(Ohun ni) Ina gbigbona gan-an
← 100 Al-Qari'ah (101/114) 102 →
Kika Surah Al-Qari'ah ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

101القارعة Al-Qari'ah 📚 11 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers