Surah Al-'Adiyat ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-'Adiyat pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (11 Ẹsẹ — مكية). Al-'Adiyat Gbọ, Al-'Adiyat Itumọ, Al-'Adiyat mp3, Al-'Adiyat pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-'Adiyat

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
وَالْعَادِيَاتِ ضَبْحًا ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Allahu bura pelu awon esin t’o n sare t’o n mi helehele ni oju-ogun
فَالْمُورِيَاتِ قَدْحًا ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
O tun bura pelu awon esin ti patako ese won n sana (nibi ere sisa)
فَالْمُغِيرَاتِ صُبْحًا ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
O tun bura pelu awon esin t’o n kolu ota esin ni owuro kutukutu
فَأَثَرْنَ بِهِ نَقْعًا ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Won si fi (patako ese won) tu eruku (ile ota) soke
فَوَسَطْنَ بِهِ جَمْعًا ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Won tun be gija papo pelu re saaarin akojo ota
إِنَّ الْإِنسَانَ لِرَبِّهِ لَكَنُودٌ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Dajudaju eniyan ni alaimoore si Oluwa re
وَإِنَّهُ عَلَىٰ ذَٰلِكَ لَشَهِيدٌ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
Dajudaju Allahu si n je Elerii lori iyen
وَإِنَّهُ لِحُبِّ الْخَيْرِ لَشَدِيدٌ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Ati pe dajudaju eniyan le gan-an nibi ife oore aye
۞ أَفَلَا يَعْلَمُ إِذَا بُعْثِرَ مَا فِي الْقُبُورِ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
Se ko mo pe nigba ti won ba tu ohun t’o wa ninu saree jade (fun ajinde)
وَحُصِّلَ مَا فِي الصُّدُورِ ۝١٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 10
ti won si tu ohun t’o wa ninu igba-aya eda sita patapata
إِنَّ رَبَّهُم بِهِمْ يَوْمَئِذٍ لَّخَبِيرٌ ۝١١
📖 Itumọ Ẹsẹ 11
dajudaju Oluwa won ni Alamotan nipa won ni Ojo yen
← 99 Al-'Adiyat (100/114) 101 →
Kika Surah Al-'Adiyat ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

100العاديات Al-'Adiyat 📚 11 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Al-'Adiyat — 11 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers