PDF —
55 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Qamar pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Qamar pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Qamar Itumọ. Surah Al-Qamar (Meccan) 55 Ẹsẹ.

← An-NajmSurah Al-Qamar Ar-Rahman →


55 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮬﮭﮮﮯﮰ
54:1 Akoko naa sunmo. Osupa si la peregede (si meji)
ﮱﯓﯔﯕﯖﯗﯘﯙ
54:2 Ti won ba ri ami kan, won maa gbunri. Won yo si wi pe: "Idan kan (t’o lagbara) t’o maa lo ni
ﯚﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡ
54:3 Won pe e niro. Won si tele ife-inu won. Gbogbo ise eda si maa jokoo ti i lorun
ﯢﯣﯤﯥﯦﯧﯨﯩ
54:4 Dajudaju eyi ti won fi ohun lile ko wa ninu awon iro t’o de ba won
ﯪﯫﯬﯭﯮﯯﯰ
54:5 Ijinle oye t’o peye ni; sugbon awon ikilo naa ko ro won loro
ﯱﯲﯳﯴﯵﯶﯷﯸﯹﯺ
54:6 Seri kuro ni odo won. Ni ojo ti olupepe yoo pepe fun kini kan ti emi korira (iyen, Ajinde)
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙ
54:7 Oju won maa wale ni ti abuku. Won yo si maa jade lati inu saree bi eni pe esu ti won fonka sita ni won
ﭚﭛﭜﭝﭞﭟﭠﭡﭢﭣ
54:8 Won yo si maa yara lo si odo olupepe naa. Awon alaigbagbo yo si wi pe: "Eyi ni ojo isoro
ﭤﭥﭦﭧﭨﭩﭪﭫﭬﭭﭮ
54:9 Ijo (Anabi) Nuh pe ododo niro siwaju won. Nigba naa, won pe erusin Wa ni opuro. Won si wi pe: "Were ni." Won si ko fun un pelu ohun lile. won fi ohun lile ko ododo sile fun Anabi Nuh (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ni kiko alesa-seyin fun won nipase siso oro buruku si i hihale mo on
ﭯﭰﭱﭲﭳﭴ
54:10 Nitori naa, o pe Oluwa re pe: "Dajudaju won ti bori mi. Ran mi lowo
ﭵﭶﭷﭸﭹﭺ
54:11 Nitori naa, A si awon ilekun sanmo sile pelu omi t’o lagbara
ﭻﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂﮃﮄ
54:12 A tun mu awon odo seyo lori ile. Omi (sanmo) pade (omi ile) pelu ase ti A ti ko (le won lori)
ﮅﮆﮇﮈﮉﮊ
54:13 A si gbe (Anabi) Nuh gun oko onipako, oko elesoo
ﮋﮌﮍﮎﮏﮐﮑ
54:14 t’o n rin (lori omi) loju Wa. (O je) esan fun eni ti won tako
ﮒﮓﮔﮕﮖﮗﮘ
54:15 Dajudaju A fi sile ni ami. Nje oluranti wa bayii bi
ﮙﮚﮛﮜﮝ
54:16 Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won)
ﮞﮟﮠﮡﮢﮣﮤﮥ
54:17 Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi
ﮦﮧﮨﮩﮪﮫﮬ
54:18 Iran ‘Ad pe ododo niro. Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won)
ﮭﮮﮯﮰﮱﯓﯔﯕﯖﯗ
54:19 Dajudaju Awa ran ategun lile si won ni ojo buruku kan t’o n te siwaju
ﯘﯙﯚﯛﯜﯝﯞ
54:20 O n fa awon eniyan jade bi eni pe kukute igi ope ti won fa tu tegbotegbo ni won
ﯟﯠﯡﯢﯣ
54:21 Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won)
ﯤﯥﯦﯧﯨﯩﯪﯫ
54:22 Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi
ﯬﯭﯮﯯ
54:23 Ijo Thamud pe awon ikilo niro
ﯰﯱﯲﯳﯴﯵﯶﯷﯸﯹﯺ
54:24 Won wi pe: "Se abara kan, eni kan soso ninu wa ni a oo maa tele. (Bi o ba ri bee) nigba naa dajudaju awa ti wa ninu isina ati iya
ﯻﯼﯽﯾﯿﰀﰁﰂﰃﰄ
54:25 Se oun ni won so iranti kale fun laaarin wa? Rara o, opuro onigbeeraga ni
ﰅﰆﰇﰈﰉﰊ
54:26 Ni ola ni won yoo mo ta ni opuro onigbeeraga
ﰋﰌﰍﰎﰏﰐﰑﰒ
54:27 Dajudaju Awa maa ran abo rakunmi si won; (o maa je) adanwo fun won. Nitori naa, maa wo won niran na, ki o si se suuru
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗﭘﭙﭚ
54:28 Ki o si fun won ni iro pe dajudaju pipin ni omi laaarin won. Gbogbo ipin omi si wa fun eni ti o ba kan lati wa si odo
ﭛﭜﭝﭞﭟ
54:29 Nigba naa ni won pe eni won. O wa ona lati mu (rakunmi naa mole). O si pa a
ﭠﭡﭢﭣﭤ
54:30 Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won)
ﭥﭦﭧﭨﭩﭪﭫﭬﭭ
54:31 Dajudaju Awa ran igbe kan soso si won. Won si da bi igi koriko gbigbe
ﭮﭯﭰﭱﭲﭳﭴﭵ
54:32 Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi
ﭶﭷﭸﭹﭺ
54:33 Ijo Lut pe awon ikilo niro
ﭻﭼﭽﭾﭿﮀﮁﮂﮃﮄﮅ
54:34 Dajudaju Awa fi okuta ina ranse si won afi ara ile Lut, ti A gbala ni asiko saari
ﮆﮇﮈﮉﮊﮋﮌﮍﮎ
54:35 (O je) ike kan lati odo Wa. Bayen ni A se n san esan fun eni t’o ba dupe (fun Wa)
ﮏﮐﮑﮒﮓﮔ
54:36 O kuku fi igbamu Wa se ikilo fun won, sugbon won ja awon ikilo niyan
ﮕﮖﮗﮘﮙﮚﮛﮜﮝﮞ
54:37 Won kuku lakaka lodo re lati ba awon alejo re sebaje. Nitori naa, A fo oju won. E to iya Mi ati ikilo Mi wo
ﮟﮠﮡﮢﮣﮤ
54:38 Ati pe dajudaju iya gbere ni won mojumo sinu re ni owuro kutukutu
ﮥﮦﮧﮨ
54:39 Nitori naa, e to iya Mi ati ikilo Mi wo
ﮩﮪﮫﮬﮭﮮﮯﮰ
54:40 Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi
ﮱﯓﯔﯕﯖﯗ
54:41 Dajudaju awon ikilo de ba awon eniyan Fir‘aon
ﯘﯙﯚﯛﯜﯝﯞﯟ
54:42 Won pe awon ayah Wa niro, gbogbo re patapata. A si gba won mu ni igbamu (ti) Alagbara, Olukapa (n gba eda mu)
ﯠﯡﯢﯣﯤﯦﯧﯨﯩﯪ
54:43 Se awon alaigbagbo (ninu) yin l’o loore julo si awon wonyen (ti won ti pare bo seyin) ni tabi eyin ni imoribo kan ninu ipin-ipin Tira (pe eyin ko nii jiya)
ﯫﯬﯭﯮﯯﯰ
54:44 Tabi won n wi pe: "Gbogbo wa ni a oo ranra wa lowo lati bori (Ojise)
ﯱﯲﯳﯴﯵ
54:45 A maa fo akojo naa logun. Won si maa fese fee loju ogun
ﯶﯷﯸﯹﯺﯻﯼ
54:46 Amo sa, Akoko naa ni ojo adehun won. Akoko naa buru julo. O si koro julo
ﯽﯾﯿﰀﰁﰂ
54:47 Dajudaju awon elese wa ninu isina (nile aye, won yo si wa ninu) Ina jijo (ni orun)
ﰃﰄﰅﰆﰇﰈﰉﰊﰋﰌ
54:48 Ni ojo ti A oo doju won dele wo inu Ina, (A o si so pe): E to ifowoba Ina wo
ﰍﰎﰏﰐﰑﰒ
54:49 Dajudaju A seda gbogbo nnkan pelu kadara
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗ
54:50 Ase Wa (fun mimu nnkan be) ko tayo (ase) eyo kan soso gege bi iseju
ﭘﭙﭚﭛﭜﭝﭞ
54:51 Ati pe dajudaju A ti pa awon iru yin re. Nje oluranti wa bayii bi
ﭟﭠﭡﭢﭣﭤ
54:52 Gbogbo nnkan ti won se nise si wa ninu ipin-ipin tira
ﭥﭦﭧﭨﭩ
54:53 Ati pe gbogbo nnkan kekere ati nnkan nla (ti won se) wa ni akosile
ﭪﭫﭬﭭﭮﭯ
54:54 Dajudaju awon oluberu (Allahu) yoo wa ninu awon Ogba (Idera) pelu awon odo (t’o n san ni isale re)
ﭰﭱﭲﭳﭴﭵﭶ
54:55 Ni ibujokoo ododo nitosi Oba Alagbara Olukapa

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers