Al-Anbiya · 3/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anbiya
لَاهِيَةً قُلُوبُهُمْ ۗ وَأَسَرُّوا النَّجْوَى الَّذِينَ ظَلَمُوا هَلْ هَٰذَا إِلَّا بَشَرٌ مِّثْلُكُمْ ۖ أَفَتَأْتُونَ السِّحْرَ وَأَنتُمْ تُبْصِرُونَ ۝٣
Laahiyatan quloobuhum; wa asarrun najwal lazeena zalamoo hal haazaa illaa basharum mislukum afataa toonas sihra wa antum tubsiroon
📖 Ni Yorùbá
Won fonufora ni. Awon t’o sabosi si fi oro ikoko (aarin ara won) pamo pe: "Se eyi tayo abara bi iru yin ni? Se e maa tele idan ni, nigba ti eyin naa riran
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 1-5 — Al-Anbiya

1اقْتَرَبَ لِلنَّاسِ حِسَابُهُمْ وَهُمْ فِي غَفْلَةٍ مُّعْرِضُونَ
Isiro-ise sunmo fun awon eniyan, won si wa ninu ifonufora, ti won n gbunri (kuro nibi ododo)
2مَا يَأْتِيهِم مِّن ذِكْرٍ مِّن رَّبِّهِم مُّحْدَثٍ إِلَّا اسْتَمَعُوهُ وَهُمْ يَلْعَبُونَ
Ko si iranti titun kan ti o maa de ba won lati odo Oluwa won afi ki won gbo o pelu ere sise
3لَاهِيَةً قُلُوبُهُمْ ۗ وَأَسَرُّوا النَّجْوَى الَّذِينَ ظَلَمُوا هَلْ هَٰذَا إِلَّا بَشَرٌ مِّثْلُكُمْ ۖ أَفَتَأْتُونَ السِّحْرَ وَأَنتُمْ تُبْصِرُونَ
Won fonufora ni. Awon t’o sabosi si fi oro ikoko (aarin ara won) pamo pe: "Se eyi tayo abara bi iru yin ni? Se e maa tele idan ni, nigba ti eyin naa riran
4قَالَ رَبِّي يَعْلَمُ الْقَوْلَ فِي السَّمَاءِ وَالْأَرْضِ ۖ وَهُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
O so pe: “Oluwa mi mo oro t’o n be ninu sanmo ati ile. Oun ni Olugbo, Onimo.”
5بَلْ قَالُوا أَضْغَاثُ أَحْلَامٍ بَلِ افْتَرَاهُ بَلْ هُوَ شَاعِرٌ فَلْيَأْتِنَا بِآيَةٍ كَمَا أُرْسِلَ الْأَوَّلُونَ
Rara, won tun wi pe: “Awon ala ti itumo re lopo mora won ni (al-Ƙur’an.” Won tun wi pe): “Rara, o hun un ni.” (Won tun wi pe): “Rara, elewi ni. Bi bee ko ki o mu ami kan wa fun wa gege bi won se fi ran awon eni akoko.”
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
3Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 3

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 3 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won fonufora ni. Awon t’o sabosi si fi oro ikoko…

Surah Ẹsẹ 3/112 — Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anbiya Gbọ, Al-Anbiya Itumọ, Al-Anbiya mp3, Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 1–5. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers