Al-Furqan · 69/77
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Furqan
يُضَاعَفْ لَهُ الْعَذَابُ يَوْمَ الْقِيَامَةِ وَيَخْلُدْ فِيهِ مُهَانًا ۝٦٩
Yudaa`af lahul `azaabu Yawmal Qiyaamati wa yakhlud feehee muhaanaa
📖 Ni Yorùbá
A oo se iya ni ilopo fun un ni Ojo Ajinde. O si maa se gbere ninu re ni eni yepere

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 67-71 — Surah Al-Furqan

67وَالَّذِينَ إِذَا أَنفَقُوا لَمْ يُسْرِفُوا وَلَمْ يَقْتُرُوا وَكَانَ بَيْنَ ذَٰلِكَ قَوَامًا
Awon ti o je pe nigba ti won ba nawo, won ko na ina-apa, won ko si sahun; (inawo won) wa laaarin iyen ni iwontun-wonsi
68وَالَّذِينَ لَا يَدْعُونَ مَعَ اللَّهِ إِلَٰهًا آخَرَ وَلَا يَقْتُلُونَ النَّفْسَ الَّتِي حَرَّمَ اللَّهُ إِلَّا بِالْحَقِّ وَلَا يَزْنُونَ ۚ وَمَن يَفْعَلْ ذَٰلِكَ يَلْقَ أَثَامًا
(Awon ni) awon ti ko pe olohun miiran mo Allahu. Won ko pa emi ti Allahu se (pipa re) ni eewo afi ni ona eto. Ati pe won ko se zina. Enikeni ti o ba se (aburu) yen, o maa pade (iya) ese
69يُضَاعَفْ لَهُ الْعَذَابُ يَوْمَ الْقِيَامَةِ وَيَخْلُدْ فِيهِ مُهَانًا
A oo se iya ni ilopo fun un ni Ojo Ajinde. O si maa se gbere ninu re ni eni yepere
70إِلَّا مَن تَابَ وَآمَنَ وَعَمِلَ عَمَلًا صَالِحًا فَأُولَٰئِكَ يُبَدِّلُ اللَّهُ سَيِّئَاتِهِمْ حَسَنَاتٍ ۗ وَكَانَ اللَّهُ غَفُورًا رَّحِيمًا
Afi eni ti o ba ronu piwada, ti o gbagbo ni ododo, ti o si se ise rere. Awon wonyen ni Allahu yoo fi ise rere ropo ise aburu won (iyen, nipa ironupiwada won). Allahu si n je Alaforijin, Asake-orun
71وَمَن تَابَ وَعَمِلَ صَالِحًا فَإِنَّهُ يَتُوبُ إِلَى اللَّهِ مَتَابًا
Enikeni ti o ba ronu piwada, ti o si se ise rere, (ki o mo) pe dajudaju o n ronu piwada patapata sodo Allahu ni
Al-FurqanAtokọ Kurani
77Ẹsẹ
MeccanRevelation
69Ẹsẹ

Itumọ — Al-Furqan 69

Surah Al-Furqan Ẹsẹ 69 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : A oo se iya ni ilopo fun un ni Ojo…

Surah Ẹsẹ 69/77 — Surah Al-Furqan الفرقان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Furqan Gbọ, Surah Al-Furqan Itumọ, Surah Al-Furqan mp3, Surah Al-Furqan pdf. Ẹsẹ 67–71. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers