Aal-Imran · 110/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
كُنتُمْ خَيْرَ أُمَّةٍ أُخْرِجَتْ لِلنَّاسِ تَأْمُرُونَ بِالْمَعْرُوفِ وَتَنْهَوْنَ عَنِ الْمُنكَرِ وَتُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ ۗ وَلَوْ آمَنَ أَهْلُ الْكِتَابِ لَكَانَ خَيْرًا لَّهُم ۚ مِّنْهُمُ الْمُؤْمِنُونَ وَأَكْثَرُهُمُ الْفَاسِقُونَ ۝١١٠
Kuntum khaira ummatin ukhrijat linnaasi taamuroona bilma`roofi wa tanhawna `anil munkari wa tu`minoona billaah; wa law aamana Ahlul Kitaabi lakaana khairal lahum minhumul mu`minoona wa aksaruhumul faasiqoon
📖 Ni Yorùbá
E je ijo t’o loore julo, ti A gbe dide fun awon eniyan; e n pase ohun rere, e n ko ohun buruku, e si gbagbo ninu Allahu. Ti o ba je pe awon ahlul-kitab gbagbo lododo ni, iba loore julo fun won. Onigbagbo ododo wa ninu won , opolopo won si ni obileje

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 108-112 — Surah Aal-Imran

108تِلْكَ آيَاتُ اللَّهِ نَتْلُوهَا عَلَيْكَ بِالْحَقِّ ۗ وَمَا اللَّهُ يُرِيدُ ظُلْمًا لِّلْعَالَمِينَ
Iwonyi ni awon ayah Allahu, ti A n ke e fun o pelu ododo. Allahu ko si gbero abosi kan si gbogbo eda
109وَلِلَّهِ مَا فِي السَّمَاوَاتِ وَمَا فِي الْأَرْضِ ۚ وَإِلَى اللَّهِ تُرْجَعُ الْأُمُورُ
Ti Allahu ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o wa ninu ile. Odo Allahu si ni won maa seri awon oro eda pada si
110كُنتُمْ خَيْرَ أُمَّةٍ أُخْرِجَتْ لِلنَّاسِ تَأْمُرُونَ بِالْمَعْرُوفِ وَتَنْهَوْنَ عَنِ الْمُنكَرِ وَتُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ ۗ وَلَوْ آمَنَ أَهْلُ الْكِتَابِ لَكَانَ خَيْرًا لَّهُم ۚ مِّنْهُمُ الْمُؤْمِنُونَ وَأَكْثَرُهُمُ الْفَاسِقُونَ
E je ijo t’o loore julo, ti A gbe dide fun awon eniyan; e n pase ohun rere, e n ko ohun buruku, e si gbagbo ninu Allahu. Ti o ba je pe awon ahlul-kitab gbagbo lododo ni, iba loore julo fun won. Onigbagbo ododo wa ninu won , opolopo won si ni obileje
111لَن يَضُرُّوكُمْ إِلَّا أَذًى ۖ وَإِن يُقَاتِلُوكُمْ يُوَلُّوكُمُ الْأَدْبَارَ ثُمَّ لَا يُنصَرُونَ
Won ko nii ko inira ba yin ayafi ipalara die. Ti won ba si ba yin ja, won a sa fun yin. Leyin naa, A o nii ran won lowo
112ضُرِبَتْ عَلَيْهِمُ الذِّلَّةُ أَيْنَ مَا ثُقِفُوا إِلَّا بِحَبْلٍ مِّنَ اللَّهِ وَحَبْلٍ مِّنَ النَّاسِ وَبَاءُوا بِغَضَبٍ مِّنَ اللَّهِ وَضُرِبَتْ عَلَيْهِمُ الْمَسْكَنَةُ ۚ ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمْ كَانُوا يَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَيَقْتُلُونَ الْأَنبِيَاءَ بِغَيْرِ حَقٍّ ۚ ذَٰلِكَ بِمَا عَصَوا وَّكَانُوا يَعْتَدُونَ
Abuku yoo maa ba won nibikibi ti owo awon (musulumi) ba ti ba won afi (ti won ba n be) pelu aabo lati odo Allahu (iyen ni pe, ki won gba ’Islam) ati aabo lati odo awon eniyan (iyen ni pe, ki won gba lati maa san owo isakole fun ijoba ’Islam). Won seri pada pelu ibinu lati odo Allahu. Won si ko osi ba won. Iyen nitori pe, dajudaju won sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, won tun n pa awon Anabi lai letoo. Iyen nitori pe, won yapa (ase Allahu), won si n tayo enu ala
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
110Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 110

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 110 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E je ijo t’o loore julo, ti A gbe dide…

Surah Ẹsẹ 110/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 108–112. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers