Aal-Imran · 8/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
رَبَّنَا لَا تُزِغْ قُلُوبَنَا بَعْدَ إِذْ هَدَيْتَنَا وَهَبْ لَنَا مِن لَّدُنكَ رَحْمَةً ۚ إِنَّكَ أَنتَ الْوَهَّابُ ۝٨
Rabbanaa laa tuzigh quloobanaa ba`da iz hadaitanaa wa hab lanaa mil ladunka rahmah; innaka antal Wahhaab
📖 Ni Yorùbá
Oluwa wa, ma se yi wa lokan pada leyin ti O ti to wa sona. Ta wa lore ike lati odo Re, dajudaju Iwo ni Olore

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 6-10 — Surah Aal-Imran

6هُوَ الَّذِي يُصَوِّرُكُمْ فِي الْأَرْحَامِ كَيْفَ يَشَاءُ ۚ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Oun ni Eni ti O n yaworan yin sinu apoluke bi O se fe. Ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alagbara Ologbon
7هُوَ الَّذِي أَنزَلَ عَلَيْكَ الْكِتَابَ مِنْهُ آيَاتٌ مُّحْكَمَاتٌ هُنَّ أُمُّ الْكِتَابِ وَأُخَرُ مُتَشَابِهَاتٌ ۖ فَأَمَّا الَّذِينَ فِي قُلُوبِهِمْ زَيْغٌ فَيَتَّبِعُونَ مَا تَشَابَهَ مِنْهُ ابْتِغَاءَ الْفِتْنَةِ وَابْتِغَاءَ تَأْوِيلِهِ ۗ وَمَا يَعْلَمُ تَأْوِيلَهُ إِلَّا اللَّهُ ۗ وَالرَّاسِخُونَ فِي الْعِلْمِ يَقُولُونَ آمَنَّا بِهِ كُلٌّ مِّنْ عِندِ رَبِّنَا ۗ وَمَا يَذَّكَّرُ إِلَّا أُولُو الْأَلْبَابِ
Oun ni Eni ti O so Tira kale fun o; awon ayah alainipon-na wa ninu re - awon si ni ipile Tira -, onipon-na si ni iyoku. Ni ti awon ti igbunri kuro nibi ododo wa ninu okan won, won yoo maa tele eyi t’o ni pon-na ninu re lati fi wa wahala ati lati fi wa itumo (odi) fun un. Ko si si eni t’o nimo itumo re afi Allahu. Awon agba ninu imo esin, won n so pe: “A gba a gbo. Lati odo Oluwa wa ni gbogbo re (ti sokale).” Ko si eni t’o n lo iranti ayafi awon onilaakaye. ko si ayah tabi hadith kan ti o ni pon-na ti itakora won wa wo ipo “itakora toribee” (at-ta‘arudu al-haƙiƙiy). Eyi wa ni ibamu si surah an-Nisa’
8رَبَّنَا لَا تُزِغْ قُلُوبَنَا بَعْدَ إِذْ هَدَيْتَنَا وَهَبْ لَنَا مِن لَّدُنكَ رَحْمَةً ۚ إِنَّكَ أَنتَ الْوَهَّابُ
Oluwa wa, ma se yi wa lokan pada leyin ti O ti to wa sona. Ta wa lore ike lati odo Re, dajudaju Iwo ni Olore
9رَبَّنَا إِنَّكَ جَامِعُ النَّاسِ لِيَوْمٍ لَّا رَيْبَ فِيهِ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُخْلِفُ الْمِيعَادَ
Oluwa wa, dajudaju Iwo l’O maa ko awon eniyan jo ni ojo kan, ti ko si iyemeji ninu re. Dajudaju Allahu ki i ye adehun
10إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا لَن تُغْنِيَ عَنْهُمْ أَمْوَالُهُمْ وَلَا أَوْلَادُهُم مِّنَ اللَّهِ شَيْئًا ۖ وَأُولَٰئِكَ هُمْ وَقُودُ النَّارِ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, awon dukia won ati awon omo won ko nii ro won loro kini kan lodo Allahu. Awon wonyen, awon ni nnkan ikona
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
8Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 8

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 8 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Oluwa wa, ma se yi wa lokan pada leyin ti…

Surah Ẹsẹ 8/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 6–10. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers