Fussilat · 30/54
Itumọ Aṣẹ ohun — Fussilat
إِنَّ الَّذِينَ قَالُوا رَبُّنَا اللَّهُ ثُمَّ اسْتَقَامُوا تَتَنَزَّلُ عَلَيْهِمُ الْمَلَائِكَةُ أَلَّا تَخَافُوا وَلَا تَحْزَنُوا وَأَبْشِرُوا بِالْجَنَّةِ الَّتِي كُنتُمْ تُوعَدُونَ ۝٣٠
Innal lazeena qaaloo Rabbunal laahu summas taqaamoo tatanazzalu `alaihimul malaaa `ikatu allaa takhaafoo wa laa tahzanoo wa abshiroo bil Jannnatil latee kuntum too`adoon
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon t’o so pe: "Allahu ni Oluwa wa." leyin naa, ti won duro sinsin, awon molaika yoo maa sokale wa ba won (ni ojo iku won, won si maa so pe: “E ma se paya, e ma se banuje. Ki e si dunnu si Ogba Idera eyi ti Won n se ni adehun fun yin)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 28-32 — Fussilat

28ذَٰلِكَ جَزَاءُ أَعْدَاءِ اللَّهِ النَّارُ ۖ لَهُمْ فِيهَا دَارُ الْخُلْدِ ۖ جَزَاءً بِمَا كَانُوا بِآيَاتِنَا يَجْحَدُونَ
Ina, iyen ni esan awon ota Allahu. Ile gbere wa ninu re fun won. O je esan nitori pe won n tako awon ayah Wa
29وَقَالَ الَّذِينَ كَفَرُوا رَبَّنَا أَرِنَا اللَّذَيْنِ أَضَلَّانَا مِنَ الْجِنِّ وَالْإِنسِ نَجْعَلْهُمَا تَحْتَ أَقْدَامِنَا لِيَكُونَا مِنَ الْأَسْفَلِينَ
Awon t’o sai gbagbo wi pe: "Oluwa wa, fi awon mejeeji ti won si wa lona ninu awon alujannu ati eniyan han wa nitori ki a le fi awon mejeeji si abe gigise wa, nitori ki won le wa ni isale patapata
30إِنَّ الَّذِينَ قَالُوا رَبُّنَا اللَّهُ ثُمَّ اسْتَقَامُوا تَتَنَزَّلُ عَلَيْهِمُ الْمَلَائِكَةُ أَلَّا تَخَافُوا وَلَا تَحْزَنُوا وَأَبْشِرُوا بِالْجَنَّةِ الَّتِي كُنتُمْ تُوعَدُونَ
Dajudaju awon t’o so pe: "Allahu ni Oluwa wa." leyin naa, ti won duro sinsin, awon molaika yoo maa sokale wa ba won (ni ojo iku won, won si maa so pe: “E ma se paya, e ma se banuje. Ki e si dunnu si Ogba Idera eyi ti Won n se ni adehun fun yin)
31نَحْنُ أَوْلِيَاؤُكُمْ فِي الْحَيَاةِ الدُّنْيَا وَفِي الْآخِرَةِ ۖ وَلَكُمْ فِيهَا مَا تَشْتَهِي أَنفُسُكُمْ وَلَكُمْ فِيهَا مَا تَدَّعُونَ
Awa ni ore yin ninu isemi aye ati ni orun. Ohun ti emi yin n fe ti wa fun yin ninu Ogba Idera. Ohun ti e n beere fun si ti wa ninu re
32نُزُلًا مِّنْ غَفُورٍ رَّحِيمٍ
Nnkan igbalejo ni lati odo Alaforijin, Asake-orun.”
FussilatAtokọ Kurani
54Ẹsẹ
MeccanRevelation
30Ẹsẹ

Itumọ — Fussilat 30

Surah Fussilat Ẹsẹ 30 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon t’o so pe: "Allahu ni Oluwa wa." leyin…

Surah Ẹsẹ 30/54 — Fussilat فصلت (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Fussilat Gbọ, Fussilat Itumọ, Fussilat mp3, Fussilat pdf. Ẹsẹ 28–32. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers