PDF —
11 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-'Adiyat pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-'Adiyat pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-'Adiyat Itumọ. Surah Al-'Adiyat (Meccan) 11 Ẹsẹ.



11 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﮱﯓﯔ
100:1 Allahu bura pelu awon esin t’o n sare t’o n mi helehele ni oju-ogun
ﯕﯖﯗ
100:2 O tun bura pelu awon esin ti patako ese won n sana (nibi ere sisa)
ﯘﯙﯚ
100:3 O tun bura pelu awon esin t’o n kolu ota esin ni owuro kutukutu
ﯛﯜﯝﯞ
100:4 Won si fi (patako ese won) tu eruku (ile ota) soke
ﯟﯠﯡﯢ
100:5 Won tun be gija papo pelu re saaarin akojo ota
ﭑﭒﭓﭔﭕ
100:6 Dajudaju eniyan ni alaimoore si Oluwa re
ﭖﭗﭘﭙﭚ
100:7 Dajudaju Allahu si n je Elerii lori iyen
ﭛﭜﭝﭞﭟ
100:8 Ati pe dajudaju eniyan le gan-an nibi ife oore aye
ﭠﭡﭢﭣﭤﭥﭦﭧﭨ
100:9 Se ko mo pe nigba ti won ba tu ohun t’o wa ninu saree jade (fun ajinde)
ﭩﭪﭫﭬﭭ
100:10 ti won si tu ohun t’o wa ninu igba-aya eda sita patapata
ﭮﭯﭰﭱﭲﭳ
100:11 dajudaju Oluwa won ni Alamotan nipa won ni Ojo yen

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers