8 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﯝﯞﯟﯠﯡ
94:1 Se A o sipaya igba-aya re fun o bi
ﯢﯣﯤﯥ
94:2 A si gbe ese re kuro lorun re
ﭑﭒﭓﭔ
94:3 eyi ti o wo o lorun. amo ti onitoun pada gba ’Islam ibaa je pe o gba a ni owuro
ﭕﭖﭗﭘ
94:4 A si gbe iranti oruko re ga fun o
ﭙﭚﭛﭜﭝ
94:5 Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira
ﭞﭟﭠﭡﭢ
94:6 Dajudaju idekun wa leyin inira se
ﭣﭤﭥﭦ
94:7 Nitori naa, nigba ti o ba buse (lori okan), gbiyanju (omiran)
ﭧﭨﭩﭪ
94:8 Odo Oluwa re si ni ki o soju kokoro oore si

Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers