Surah At-Tin pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah At-Tin pdf Yorùbá — Gbà Surah At-Tin Itumọ. Surah At-Tin (Meccan) 8 Ẹsẹ.
Related
- Surah At-Tin ItumọYorùbá
- Surah At-Tin mp3Gbọ
- Quran Index Yorùbá114
More Surah PDF
Surah At-Tin

ﭫﭬﭭ
95:1
Allahu bura pelu eso tin ati eso zaetun
ﭮﭯﭰ
95:2
O tun bura pelu apata Sinin
ﭱﭲﭳﭴ
95:3
O tun bura pelu ilu ifayabale yii
ﭵﭶﭷﭸﭹﭺﭻ
95:4
Dajudaju A seda eniyan pelu irisi t’o dara julo
ﭼﭽﭾﭿﮀ
95:5
Leyin naa, A maa da a pada si isale patapata (ninu Ina)
ﮁﮂﮃﮄﮅﮆﮇﮈﮉﮊ
95:6
Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere. Nitori naa, esan ti ko nii pin (ti ko nii pedin) n be fun won
ﮋﮌﮍﮎﮏ
95:7
Ta l’o tun n pe o ni opuro nipa Ojo esan leyin (oro yii)
ﮐﮑﮒﮓﮔ
95:8
Se Allahu ko ni Eni t’O mo ejo da julo ninu awon adajo ni
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







