Surah Ad-Duha pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah Ad-Duha pdf Yorùbá — Gbà Surah Ad-Duha Itumọ. Surah Ad-Duha (Meccan) 11 Ẹsẹ.
Related
- Surah Ad-Duha ItumọYorùbá
- Surah Ad-Duha mp3Gbọ
- Quran Index Yorùbá114
More Surah PDF
Surah Ad-Duha

ﮉﮊ
93:1
(Allahu bura pelu) iyaleta
ﮋﮌﮍﮎ
93:2
O tun bura pelu ale nigba ti (ile) ba su
ﮏﮐﮑﮒﮓﮔ
93:3
Oluwa re ko pa o ti, ko si binu si o
ﮕﮖﮗﮘﮙﮚ
93:4
Dajudaju orun loore fun o ju aye lo
ﮛﮜﮝﮞﮟ
93:5
Dajudaju laipe Oluwa re maa fun o ni (oore pupo ni orun). Nitori naa, o si maa yonu si i
ﮠﮡﮢﮣﮤ
93:6
Se (Allahu) ko ri o ni omo-orukan ni? O si fun o ni ibugbe
ﮥﮦﮧﮨ
93:7
O si ri o ni alaimona (iyen siwaju isokale imisi). O si fi ona mo o
ﮩﮪﮫﮬ
93:8
O tun ri o ni alaini, O si ro o loro
ﮭﮮﮯﮰﮱ
93:9
Nitori naa, ni ti omo-orukan, ma se je gaba (le e lori)
ﯓﯔﯕﯖﯗ
93:10
Ni ti alagbe, ma si se jagbe (mo on)
ﯘﯙﯚﯛﯜ
93:11
Ni ti idera Oluwa re, so o jade
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







